Bala Mohammed

Olóṣèlú

Bala Mohammed jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]

Bala Abdulkadir Mohammed
Aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2007 – Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹrin Ọdún 2010
AsíwájúAbubakar Maikafi
Arọ́pòAdamu Gumba
Mínísítà fún Àbújá
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹrin Ọdún 2010
AsíwájúAdamu Aliero
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kẹ̀wá 1958 (1958-10-05) (ọmọ ọdún 66)
Alkedim tàbí Alakaleri, Bauchi State

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Turaki A. Hassan (21 March 2010). "Yuguda behind my recall move – Sen Moh’d". media Daily Trust. Retrieved 2011-10-13.