Adamu adamu
Oníwé-Ìròyín
Mallam Adamu Adamu CON[1] (tí a bí ní 25 May 1954) jẹ́ Ọ̀mọ̀wé onisiro àti Oniroyin ní Naijiria, òun ní Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ lowolowo ní Naijiria .[2][3][4][5]
Mallam Adamu Adamu | |
---|---|
Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 11 November 2015 | |
Ààrẹ | Muhammadu Buhari |
Asíwájú | Ibrahim Shekarau àtiNyesom Wike (ni ọdún 2014) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kàrún 1954 Azare, àríwá Nàìjíríà, British Nigeria (now Azare, Katagum, Bauchi State, Nigeria) |
Alma mater | Ahmadu Bello University Columbia University |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeA bí Adamu ni ọjọ́ karundilogbon oṣù karun(25 May) ọdun 1954, in Azare.[6] Ó gba àmì ẹyẹ nínú ìmò ìṣirò ní Yunifásitì ti Ahmadu Bello, Zaria. Ó tún padà gba àmì ẹyẹ master's degree nínú ìmò ìròyìn ni School of Journalism ti Yunifásitì Columbia[7][8] Ó le sọ èdè púpò, èdè bi Hausa, Inglisi, Persian, Arabic àti French.[7] Ó wá láti ìpínlè Bauchi, Nàìjíríà.[9]
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "FULL LIST: Okonjo-Iweala, Abba Kyari... FG nominates 437 persons for national honours". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-10-02. Retrieved 2022-10-13.
- ↑ "Jubilation at Education Ministry as Adamu takes over". dailypost.ng. Daily Post. Retrieved 3 October 2017.
- ↑ "ASUU: FG sets up visitation panels, whitepaper committees". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-18. Retrieved 2022-02-22.
- ↑ "FG will continue to invest big in education, says Minister". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-13. Archived from the original on 21 June 2022. Retrieved 2022-06-21.
- ↑ "What changed Mallam Adamu Adamu’s position on Asuu - was it office? The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-20. Retrieved 2022-06-21.
- ↑ "Profile of Minister of Education, Mallam Adamu Adamu". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-21. Retrieved 2020-02-07.
- ↑ 7.0 7.1 "Executives-Ministry of Education". nigeria.gov.ng. Federal Government of Nigeria. Archived from the original on 3 October 2017. Retrieved 3 October 2017.
- ↑ "FOR THE RECORD: Official citations of Buhari’s ministers, SGF - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-21. Retrieved 2022-06-21.
- ↑ "Biography of Adamu Adamu". biography.hi7.co. Retrieved 2022-03-07.