Adenike Akinsemolu
Adenike Adebukola Akinsemolu jẹ́ olùkọ́ni nípa àyíká Nàìjíríà àti oníṣòwò àwùjọ.[1] Adenike jẹ̀ olùkọ́ni ní Yunifásítì Obafemi Awolowo (Ilé-ìwé kólẹ́jì Adeyemi). Ó jẹ́ gbajúmọ̀ nípa asíwájú onímọ̀ lórí ètò àyíká. [1] [2] [3]
Adenike jẹ́ olùdásílẹ̀ Green Campus Initiative, tí ó di Ilé Ẹ̀kọ́ Green tí o ń ṣe agbero fún àyíká, àkókò irú rẹ̀ ni ọgbà ilé-ìwé gíga ní Nàìjíríà.[4][5] Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ Girl Prize tí ń pèsè ìránlọ́wọ́ ti owó àti ẹ̀kọ́ fún àwọn ọmọbìnrin ilé ìwé gírámà ní Nàìjíríà.[4]
Akinsemolu ti gba àmì ẹ̀yẹ ti Robert Bosch Stiftung Award àti àmì ẹ̀yẹ ti Nigeria Energy Award.[6]
Ó jẹ́ onkòwé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé tí a ti ṣe àtẹ́jáde wọ́n ní àwọn ìwé tó jẹ́ mọ́ ẹ̀kọ́ academic journals, àti ìwé lórí àwọn ojúṣe àwọn kòkòrò tí a kò lè fojú rí microorganisms láti mú sustainable development goals.[7][8]
Iṣẹ́ Rẹ̀
àtúnṣeA bí Adenike Akinsemolu ni Ìpínlẹ̀ Ondo, Nàìjíríà. Ó gba Master's àti òye Ph.D rẹ̀ ni Environmental Microbiology[9][10] láti Yunifásítì Babcock àti Federal University of Technology, pẹ̀lú postgraduate diploma nínú Ẹ̀kọ́ ní Yunifásítì Ọbafemi Awolowo.[11] Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Clinton Foundation ní New York, kí ó tó wà dá Green Campus Initiative sílẹ̀.[12][13]
Akinsemolu jẹ́ aláábaṣepọ ẹgbẹ́ Royal Commonwealth Society, àti ọmọ ẹgbẹ́ National Steering Committee of the Sustainable Energy Practitioners Association of Nigeria (SEPAN) lábẹ́ ọ́fíísì alákòóso iná àti agbára.[14][15] Ó jẹ́ olùṣe wádìí tó gba àmì ẹ̀yẹ Robert Bosch Stiftung.[16][17] Ní oṣù kẹwàá, ọdún 2015,ó gba àmì ẹ̀yẹ Nigeria Energy Awards fún Energy Efficiency àti Advocacy.[18][19]
Ó ja ìjà fún Ìfíkún ẹ̀kọ́ lórí ikòríko àti alágbero rẹ̀ nínú ètò ẹ̀kọ́ ti àwọn ilé ìwé Nàìjíríà .[20] In 2015, Sahara Reporters did a documentary on her Green Journey.[21][22]
Akinsemolu ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí aláábasepọ̀ ti ẹ̀kọ́ pẹ̀lú United Nations Sustainable Development Solutions Network àti ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì fún ti 6th Annual International Conference on Sustainable Development (ICSD), ní The Earth Institute, Yunifásítì Columbia.[17] In 2020, Akinsemolu published the book: "The Principles of Green and Sustainability Science," that examines sustainability issues in Africa.[23][10]
Ní oṣù kẹta ọdún 2021, a ṣe ìdánimọ̀ fún Akinsemolu gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn adarí ọ̀dọ́ nínú ìtọ́jú àyíká, ó si di ọ̀kan lára àwọn ọmọ Nàìjíríà tí ó pogoja lára àwọn Africa’s Top 100 Young Conservation Leaders award[24][25] by the Africa Alliance of the YMCA, the World Organization of the Scout Movement, the African Wildlife Foundation and World Wildlife Fund.[26][27]
Ilé Iṣẹ́ Green
àtúnṣeNí ọdún 2015, Akinsemolu dá Green Campus Initiative (GCI) sílẹ̀, tí ó sì jẹ́ ilé iṣẹ́ àkọ́kọ́ fún àgbẹ́nusọ́ ìtọ́jú àgbègbè wa nínú ọgbà Yunifásítì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[28]. A ṣe àfihàn fún ètò ilé iṣẹ́ náà ní Fourth Annual Green Campuses Conference, ọdún 2015, ní Yunifásítì ti Western Cape ní Ìhà Ìwọ̀ Gúúsù ni Áfríkà, pẹ̀lú àmì ẹ̀yẹ fún iṣẹ́ àgbè ti ọgbà Yunifásítì.[18] GCI is a member of the UN Sustainable Development Solutions Network.[17]. Ní ọdún 2016, Green Campus Initiative dàgbà di Green Institute, ilé iṣẹ́ fún ìwádìí alágbéró àti ìkọ́ni pẹ̀lú iṣẹ́ àwùjọ. Ọ̀jọ̀gbọ́n Damilola S. Olawuyi di Ààrẹ àkọ́kọ́ tí ilé iṣẹ́ náà. Ilé Iṣẹ́ pèsè ẹ̀kọ́ lórí Alágbéró àti Iṣẹ́ ṣíṣe fún ìdàgbàsókè àwùjọ ìṣòwò, tí ó wà ní ìlànà pẹ̀lú United Nations Sustainable Development Goals.[23][29]. Ilé Iṣẹ́ náà jẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà láti pèsè owó ẹ̀kọ́ fún agbátẹ̀rù ẹ̀kọ́ lórí ìtọ́jú ìdọ̀tí tí wọ́n pè ní "Trash for education", tí ń pèsè owó fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n bá mú ìdọ̀tí tí wọ́n ṣà jọ wá èyí tí ìjọba ti Ìpínlẹ̀ àti ilé iṣẹ́ àdáni yóò rà.[30][31]
Ní oṣù kẹfà, ọdún 2020, Ilé Iṣẹ́ Green ṣe ìpàdé lórí àgbéró ti gbogbo àgbáyé ni ọjọ́ World Environment Day (ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹfà), wọ́n sì ṣe àkójọ àwọn adarí àgbéró ó lé ní márùnlélógún láti orílẹ̀ èdè onírúurú tí gbajúgbajà lórí ètò ìṣúná tí àgbègbè Jeffrey Sachs sì wà níbẹ̀. [32]
Ọ̀rọ̀ Àwùjọ=
àtúnṣeAkinsemolu ti ṣe agbátẹ̀rù ẹ̀kọ́ fún àwọn ọmọbìnrin, ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ "Girl Prize," ètò ìrànlọ́wọ̀ ẹ̀kọ́ àti ìkọ́ni .[9][33] Ó kópa nínú iṣẹ́ ìran ni lọ́wọ́ ti Clinton Foundation, lẹ́yìn 2004 Indian Ocean earthquake àtu Hurricane Katrina ní New Orleans.[34]
Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ Rẹ̀
àtúnṣe- Robert Bosch Stiftung Young Researcher Award.
- Nigeria Energy Awards for Energy Efficiency and Advocacy, 2015.
- Member of the National Steering Committee of the Sustainable Energy Practitioners Association of Nigeria (SEPAN)
- Academic Associate with the United Nations Sustainable Development Solutions Network.
- Scientific Committee Member of the 6th Annual International Conference on Sustainable Development (ICSD)
Àwọn Ìwé tí ó Tẹ̀jáde
àtúnṣeÌwé Lórí Ẹ̀kọ́
àtúnṣe- Akinsemolu, Adenike A. (2018-05-01). "The role of microorganisms in achieving the sustainable development goals". Journal of Cleaner Production 182: 139–155. doi:10.1016/j.jclepro.2018.02.081. ISSN 0959-6526. http://www.sciencedirect.com/science/article/pii/S0959652618303871.
- Akinsemolu, Adenike A.; Olukoya, Obafemi A. P. (2020-02-10). "The vulnerability of women to climate change in coastal regions of Nigeria: A case of the Ilaje community in Ondo State". Journal of Cleaner Production 246: 119015. doi:10.1016/j.jclepro.2019.119015. ISSN 0959-6526. http://www.sciencedirect.com/science/article/pii/S0959652619338855.
Ìwé
àtúnṣe- Akinsemolu, Adenike (2020). The Principles of Green and Sustainability Science. Springer Singapore. ISBN 978-981-15-2492-9. https://www.springer.com/gp/book/9789811524929.
Àwọn Ìtọ́kási
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Hawken, Melanie (2016-02-20). "The startup story of a social entrepreneur in Nigeria building a new generation of environmentally conscious student leaders". Lionesses of Africa Website. Retrieved 2018-10-13.
- ↑ Abumere, Princess Irede (2016-06-01). "New Media Conference 2016: Digital influencers get together to discuss new media in Nigeria". Pulse.ng. Retrieved 2018-10-13.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Leading Ladies Africa". Leading Ladies Africa. 2018-08-14. Retrieved 2018-10-13.
- ↑ 4.0 4.1 "Adenike Akinsemolu Biography". THE GREEN INSTITUTE. Retrieved 2023-04-15.
- ↑ Nescafé (2017-05-31). "Adenike Akinsemolu Is Saving Our Environment One University Campus At A Time" (in en-US). Konbini Nigeria. Archived from the original on 2019-07-01. https://web.archive.org/web/20190701052553/http://www.konbini.com/ng/inspiration/adenike-akinsemolu-is-saving-our-environment-one-university-campus-at-a-time/.
- ↑ "Adenike Akinsemolu". ogeesedu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-26.
- ↑ Akinsemolu, Adenike A. (2018-05-01). "The role of microorganisms in achieving the sustainable development goals" (in en). Journal of Cleaner Production 182: 139–155. doi:10.1016/j.jclepro.2018.02.081. ISSN 0959-6526. https://www.sciencedirect.com/science/article/pii/S0959652618303871.
- ↑ "Akinsemolu, Adenike A.". Scopus. Retrieved 19 May 2023.
- ↑ 9.0 9.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ 10.0 10.1 Amyx, Scott (2020-09-07). "Interview with Adenike Akinsemolu, Ph.D., Founder of the Green Institute". Scott Amyx (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-16.
- ↑ "Overview of Adenike Akinsemolu". Adeyemi College of Education. Archived from the original on 26 March 2017. Retrieved 4 April 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Green The Campus Ambassador Training Hits Adeyemi University Of Education". Sahara Reporters. 2015-12-20. Retrieved 2017-03-05.
- ↑ francis (2015-12-22). "Adeyemi College of Education hosts Green Ambassadors Training - AgroNigeria" (in en-US). AgroNigeria. http://agronigeria.com.ng/adeyemi-college-of-education-hosts-green-ambassadors-training/.
- ↑ "Trustees - SEPAN". SEPAN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-07-01. Retrieved 2017-03-05. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Gender Mainstreaming - SEPAN". SEPAN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-07-01. Retrieved 2017-03-05. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Entrepreneur Advice from Adenike Akinsemolu: Start now, start right, start proud and don't stop!". Lionesses of Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-23.
- ↑ 17.0 17.1 17.2 BellaNaija.com (2020-03-26). "These Women Are Doing Great Work For the Nigerian Education System". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-23.
- ↑ 18.0 18.1 "History". The Green Institute (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-23.
- ↑ "Press release: 2015 Nigeria Energy Awards finalist announced". Sun-Connect-News (in Èdè Jámánì). Retrieved 2021-05-28.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Akintomide, Yemi (2015-06-22). "Nigeria: Renewable Energy - Adeyemi College to Adopt Solar Power On Campus". AllAfrica.com. http://allafrica.com/stories/201506221388.html.
- ↑ SaharaTV (2015-09-05), "What It Means To Be Green And Not Boring"-Green Initiative Founder, Adenike Akinsemolu, retrieved 2017-03-05
- ↑ Ajumobi, Kemi (2019-06-07). "Adenike Adebukola Akinsemolu: Founder, The Green Institute". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-27.
- ↑ 23.0 23.1 "Who We Are". The Green Institute (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-23.
- ↑ "Top 100 Young African Conservation Leaders' List 2021". African Wildlife Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-16.
- ↑ "Young African Conservation Leaders - Dr. Adenike Akinsemolu" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Arise News. Retrieved 2022-04-16.
- ↑ "Top 100 Young African Conservation Leaders" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-04-19. Retrieved 2022-04-16.
- ↑ "Top 100 Young African Conservation Leaders | Adenike Adebukola Akinsemolu" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-04-16. Retrieved 2022-04-16. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:2
- ↑ "400 anni dopo la tratta degli schiavi, dobbiamo decolonizzare l'Africa dai nostri pregiudizi". The Vision (in Èdè Ítálì). 2019-09-04. Retrieved 2020-04-25.
- ↑ Akinosun, Grace (2017-10-25). "Startup Profile: Green Institute — exchange trash for education". Techpoint.Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-25.
- ↑ "Recycling for Education Credits". Global Opportunity Explorer (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-12. Retrieved 2021-05-28.
- ↑ "Hw to Transform UN's Environmental Goals into a People's Agenda for Africa". Inter Press Service. 2020-06-03. Retrieved 2022-04-16.
- ↑ "Go Green!". Homaj Schools, Ondo Nigeria. Homaj Schools. Archived from the original on 2016-03-25. Retrieved 4 April 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ SustyVibes (2017-02-14). "Susty Person of The Week - Adenike Akinsemolu". SustyVibes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-05-04. Retrieved 2020-04-23. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)