Damilola Sunday Olawuyi
Damilola Sunday Olawuyi, SAN, FCIArb, jẹ́ agbani-nímọ̀ràn káàkiri àgbáyé, ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ òfin, òǹkọ̀wé àti agbaniníyànjú lórí ọ̀rọ̀ epo-rọ̀bì, iná, ìwa-ohun-àlùmọ́nì àti òfin.[1] Òun ni igbá kejì adarí Yunifasiti Afe Babalola, Ado Ekiti, Nigeria . [2] Wọ́n fún ọ̀jọ̀gbọ́n Ọjọgbọn Ọlawuyi ní ìgbéga sí ipò ọ̀jọ̀gbọ́n kíkún nígbà tó wà ní ọmọdún méjìlélọ́gbọ̀n 32. Ó di ọkàn lára àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tó kéré jù lọ nínú ìtàn ìmọ̀ òfin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Damilola Sunday Olawuyi | |
---|---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù Kẹ̀wá 1, 2019 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Damilola Sunday Olawuyi 28 Oṣù Kẹjọ 1983 Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Alma mater | |
Occupation |
|
Website | damilolaolawuyi.com |
Ó di alágbàwí àgbà ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ìyẹn Senior Advocate of Nigeria ( Queen's Counsel eqv.) ní ọdún 2020, ẹni ọdún mẹ́tàdínlógójì, ó di ọmọ ilé ẹ̀kọ́ àbíkẹ́yìn tí wọ́n gbéga sí ipò àgbà agbẹjọ́rò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [4] [5] [6]
Ó jẹ́ igbá kejì alága tíInternational Law Association . [7] Ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ti ṣe iranṣẹ bi BOK Visiting International Professor (VIP) ní University of Pennsylvania Law School,
ọ̀jọ̀gbọ́n tó ṣe àbẹwò síColumbia Law School, New York,[9] China University of Political Science àti Law, IAS Vanguard Fellow ní University of Birmingham,[10] àti olùṣèwádìí àgbà ní Oxford Institute fún ẹ̀kọ́ Energy.
Ní ọdún 2019, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ṣe àbẹ̀wò sí Herbert Smith Freehills at Cambridge University.[12] Ó ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí òfin tó dá lórí ọ̀rọ̀ iná ní orílẹ̀-èdè ogójì. Ní ọdún 2020, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi amòye olómìnira lórí African Union's Working Group lórí àwọn ilé-iṣẹ́ kan, àyíká àti ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn. [13] Ní ọdún 2021, Ààrẹ Muhammadu Buhari yàn án gẹ́gẹ́ bíi ọmọ-ẹgbẹ́ igbìmọ̀ ìṣàkóso ti Nigeria Extractive Industries Transparency Initiative.[14][15] Ní ọdún 2022, ààrẹ United Nations Human Rights Council yàn án láti jẹ́ aṣojú ilẹ̀ Afirika gẹ́gẹ́ bíi Amòye olómìnira lórí ìdókòwò àti ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn. [16] Ó jẹ́ alága UNESCO lórí òfin agbègbè àti Sustainable Development ní Hamad Bin Khalifa University, Doha, Qatar.
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ jẹ́ ọmọ ìlú Igbajo ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Boluwaduro ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, [18] ìlú Ibadan ní wọ́n bí i sí. Ó gba ẹ̀kọ́ alákòóbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní INRI Nursery and Primary School, ní Ìbàdàn, ó sì lọ sí Igbinedion Secondary School, Benin City, láti lọ parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀. Ibẹ̀ sì ni ó ti jókòó láti kọ ìdánwò àṣekágbá láti gba ìwé-ẹ̀rí WAEC ní ọdún 2000. Lákòókò tí ó wà ní ilé-ìwé, wọ́n mọ̀ ọ́ sí “Authority” nítorí ìfẹ́ tó ní sí ọ̀rọ̀ ìṣèlú, òfin àti orílẹ̀-èdè. Ó máa ń fi ìtara ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé-ìròyìn tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà náà.
Awards ati iyin
àtúnṣe- 2020: Alagbawi agba ti Nigeria .
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Olawuyi: 'International law emphasizes need for consent of communities that may be affected by activity or project'". Guardian Newspaper. Guardian Newspaper. March 5, 2019. Archived from the original on December 7, 2023. Retrieved December 7, 2023.
- ↑ Nigerian Lawyers News (October 12, 2019). "Professor Damilola S Olawuyi appointed as Deputy Vice Chancellor at Afe Babalola University, Ado Ekiti". Nigerian Lawyers News. Nigerian Lawyers News.
- ↑ "PROFILE: Meet Olawuyi, Nigeria's youngest SAN who became a law professor at 32". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-21. Retrieved 2023-03-26.
- ↑ "NBA hails LPPC as Ahonaruogho, Alabi, Olawuyi, 69 others make SAN list". Nation News. 2020. https://thenationonlineng.net/nba-hails-lppc-as-ahonaruogho-alabi-olawuyi-69-others-make-san-list/.
- ↑ "Meet The Youngest Academic To Become A Senior Advocate Of Nigeria". Nigerian Lawyers. November 15, 2020. https://thenigerialawyer.com/meet-the-youngest-academic-to-become-a-senior-advocate-of-nigeria/.
- ↑ "Oyetola Congratulates Prof. Olawuyi, Adesina, Hussein On Their Elevation To SAN". The Gazelle News. November 17, 2020. https://www.thegazellenews.com/2020/11/oyetola-congratulates-prof-olawuyi-adesina-hussein-on-their-elevation-to-san/.
- ↑ "Patrons & Officers". International Law Association. International Law Association. International Law Association. Retrieved October 25, 2019.
- ↑ "Bok VIPs". www.law.upenn.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-18.
- ↑ "DR. DAMILOLA OLAWUYI JOINS SABIN CENTER AS VISITING SCHOLAR". Columbia Law School. Sabin Centre for Climate Change Law, Columbia Law School.
- ↑ "IAS Vanguard Fellow 2019". University of Birmingham. Institute for Advanced Studies, University of Birmingham. Retrieved October 30, 2019.
- ↑ "Damilola Olawuyi, Senior Visiting Research Fellow". Oxford Institute for Energy Studies. Oxford Institute for Energy Studies.
- ↑ "HBKU faculty member bags Cambridge fellowship". Qatar Peninsula News. Qatar Peninsula. August 13, 2018.
- ↑ The Nations Newspaper, The Nation Newspaper (September 22, 2020). "Olawuyi Joins AU Working Group". The Nation Newspaper. The Nation Newspaper. https://thenationonlineng.net/olawuyi-joins-au-working-group/.
- ↑ TNL, Newspaper (2021). "Buhari Appoints Olawuyi, 14 Others Into NEITI Board". TNL. TNL (TNL) (7). https://thenigerialawyer.com/buhari-appoints-olawuyi-14-others-into-neiti-board/.
- ↑ Vanguard, Newspaper (July 22, 2021). "Buhari tasks NEITI's new board on accountability of natural resource revenues". Vanguard. Vanguard Newspaper. Retrieved July 23, 2021.
- ↑ "Olawuyi to represent Africa in United Nations Working Group". https://tribuneonlineng.com/olawuyi-to-represent-africa-in-united-nations-working-group/.
- ↑ "HBKU establishes Unesco Chair on environmental law and sustainability". Gulf-Times (in Èdè Árábìkì). May 22, 2022. Retrieved 2022-05-23.
- ↑ Nigerian, Tribune (December 20, 2020). "Igbajo Town Celebrates 37-Year-Old Professor Turned SAN". Nigerian Tribune (122020). https://tribuneonlineng.com/igbajo-town-celebrates-37-year-old-professor-turned-san/.
- ↑ "U.S. Society of International Law honours Nigerian, Olawuyi". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-04-04. Archived from the original on 2023-04-06. Retrieved 2023-04-06.
- ↑ Gbenga-Ogundare, Yejide (2023-04-05). "SAN bags prestigious book prize". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-06.
- ↑ "PROFILE: Meet Olawuyi, Nigeria's youngest SAN who became a law professor at 32". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-21. Retrieved 2023-03-26.