Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ewekoro
Ewekoro jẹ́ íjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ Ògùn, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú Ìtori, ní 6°56′00″N 3°13′00″E / 6.93333°N 3.21667°E.
Ewekro | |
---|---|
Coordinates: 6°56′N 3°13′E / 6.933°N 3.217°ECoordinates: 6°56′N 3°13′E / 6.933°N 3.217°E | |
Country | Nigeria |
State | Ogun State |
Government | |
• Local Government Chairman | Adesina Sikiru Adisa (APC) |
Area | |
• Total | 594 km2 (229 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 55,156 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 112 |
ISO 3166 code | NG.OG.EW |
Ó ní agbègbè tó tó 594 km2 , ó sì ní iye ènìyàn tó tó 55,156 ní ìka-orí ti ọdún 2006.
Kóòdù ìfìwéránṣẹ́ agbègbè náà ni 112.[1]
Ìjọba ìbílẹ̀ Ewékorò kó ipa pataki nínú ètò ọrọ̀-ajé ìjọba ìbílẹ̀ nípa pípèsè Cement ti Lafarge(West Africa Portland Cement Company) Ewékorò àti ẹgbẹ́ Dangote.
Wọ́n béré sí ṣe Cement náà ní ọdún 1959 èyí tí ṣe ìbẹ̀rẹ̀ Lafarge Cement ní orílẹ̀-èdè Nigeria. Pẹ̀lú bí Ewékorò ṣe jẹ́ ìlú tó ṣì ń dàgbàsókè, ó ní àbùbá ìlú tó lè di ńlá nípa oko-owo nítorí bí ó ṣe súnmọ́ ìlú méjì tó tóbi jù ní Gúúsù iwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.
Awon itokasi
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |