Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Abẹ́òkúta

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Abẹ́òkúta jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rè wà ní ìlú Ake, lágbèbè Abeokuta 7°09′00″N 3°21′00″E / 7.15000°N 3.35000°E / 7.15000; 3.35000.

Abeokuta South
Abeokuta South is located in Nigeria
Abeokuta South
Abeokuta South
Location in Nigeria
Coordinates: 7°09′N 3°21′E / 7.150°N 3.350°E / 7.150; 3.350Coordinates: 7°09′N 3°21′E / 7.150°N 3.350°E / 7.150; 3.350
Country Nigeria
StateOgun State
Government
 • Local Government ChairmanOmolaja Ayodele Majekodunmi (APC)
 • Vice Local Government ChairmanIretiolu Lanre Sotayo (APC)
Area
 • Total71 km2 (27 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total250,278
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
110
ISO 3166 codeNG.OG.AS
Gbọ̀ngán ti Ake Abeokuta, ní ìpínlẹ̀ Ògun

Ó ní ìwọ̀ ilẹ̀ tó tóbí tó 71 km2 àti èrò ènìyàn tó tó bíi 250,278 lásìkò ìkànìyàn ti ọdún 2006

Kóòù ìfìwéránṣe ti agbègbè náà ni 110.[1]

Aṣojú agbègbè náà tẹ́lẹ̀ rí ni Dimeji Bankole, tó jẹ́ agbẹnusọ fún ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin, láti ọdún 2003 wọ 2011.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)