Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gamawa
Gamawa jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè Naijiria, ní ipinle Bauchi, tó já mọ́ Ipinle Yobe, èyí tó wà ní apá ìlà-oòrùn ti Naijiria. Olú ìlú náà wà ní ìlú Gamawa.
Gamawa | |
---|---|
LGA and town | |
Àwòrán aàfin Emir ti ìlú Gamawa | |
Coordinates: 12°08′N 10°32′E / 12.133°N 10.533°ECoordinates: 12°08′N 10°32′E / 12.133°N 10.533°E | |
Country | Nigeria |
State | Bauchi State |
Area | |
• Total | 2,925 km2 (1,129 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 286,388 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 752 |
ISO 3166 code | NG.BA.GM |
Ó ní ìwọ̀n ìtóbi tó 2,925 km2 àti èrò tó ń lọ bíi 286,388, ìyẹn ní ọdún 2006.
Àwọn èyà tó wà ní ìlú náà ni: àwọn Hausa, Fulani, Fulfulde àti Kare.[1]
Kóòdù ìfìwéráńṣé agbègbè naà 752.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "State maps". Nigerian National Bureau of Statistics. Archived from the original on 2010-05-01. Retrieved 2010-05-19. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2012-11-26. Retrieved 2009-10-20.