Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Lagelu
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Lagelu jẹ́ àgbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ni ìpínlè Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olúùlú rẹ̀ wá ni ìlú tí Ìyànà Ọffà.
Lagelu | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Kazeem Gbadamosi (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ó jẹ́ àgbègbè 338 km2km2 àti and iye ènìyàn147,957 ní òǹkà ti ọdún 2006.
A ṣe àtúnpín àgbègbè ìjọba Ìpínlẹ̀ Lágelú sì ọ̀wọ́ mẹ́rìnlá tí ń se:
Ajara/Opeodu, Apatere/Kuffi/Ogunbode/Ogo, Arulogun Ehin/Kelebe, Ejioku/Igbon/Ariku, Lagelu Market/Kajola/Gbena, Lagun, Lalupon I, Lalupon II, Lalupon III, Ofa-Igbo, Ogunjana/Olowode/Ogburo, Ogunremi/Ogunsina, Oyedeji/Olode/Kutayi, Sagbe/Pabiekun. Abúlé tí a pè ní Eleruko náà wá lábẹ́ àgbègbè ìjọba Ìpínlẹ̀ yìí. Àgbègbè ìjọba ìpínlè náà wá lábẹ́ àṣẹ alága tí a dibò fún pẹ̀lú káúsẹ́lọ̀ mẹ́rìnlá, ọ̀kan tí a yàn láti ọ̀wọ́ kànkan.
Nọ́ḿbà ìfi lẹ́tà ránṣẹ́ jẹ́ 200.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2012-11-26. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)