Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Abẹ́òkúta

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Abẹ́òkúta jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rè wà ní ìlú Akomoje, lágbèbè Abeokuta. Ó ní ìwọ̀ ilẹ̀ tó tóbí tó 808 km2 àti èrò ènìyàn tó tó bíi 201,329, lásìkò ìkarí ti ọdún 2006.

Abeokuta North
Abeokuta North is located in Nigeria
Abeokuta North
Abeokuta North
Location in Nigeria
Coordinates: 7°12′N 3°12′E / 7.200°N 3.200°E / 7.200; 3.200Coordinates: 7°12′N 3°12′E / 7.200°N 3.200°E / 7.200; 3.200
Country Nigeria
StateOgun State
Government
 • Local Government ChairmanAdebayo Ayorinde (APC)
Area
 • Total808 km2 (312 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total201,329
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
110
ISO 3166 codeNG.OG.AN

Ní agbègbè yìí, a ní Oyan Dam, tó jẹ́ orísun omi pàtàkì fún Ìpínlẹ̀ Èkó àti Abeokuta. Àwọn ará-ìlú sì gbẹ́kẹ̀le fún ẹja pípa àti ìpèsè omi.[1]

Kóòdù ìfìwéránṣe ti agbègbè náà ni 110.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. O. P. Akinwale; G. C. Oliveira; M. B. Ajayi; D. O. Akande; S. Oyebadejo; K. C. Okereke. "Squamous Cell Abnormalities in Exfoliated Cells from the Urine of Schistosoma haematobium-Infected Adults in a Rural Fishing Community in Nigeria". World Health & Population, 10(1) 2008: 18-22. Retrieved 2010-05-22.  Unknown parameter |name-list-style= ignored (help)
  2. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)