Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Abẹ́òkúta
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Guusu Abeokuta)
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Abẹ́òkúta jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rè wà ní ìlú Ake, lágbèbè Abeokuta 7°09′00″N 3°21′00″E / 7.15000°N 3.35000°E.
Abeokuta South | |
---|---|
Coordinates: 7°09′N 3°21′E / 7.150°N 3.350°ECoordinates: 7°09′N 3°21′E / 7.150°N 3.350°E | |
Country | Nigeria |
State | Ogun State |
Government | |
• Local Government Chairman | Omolaja Ayodele Majekodunmi (APC) |
• Vice Local Government Chairman | Iretiolu Lanre Sotayo (APC) |
Area | |
• Total | 71 km2 (27 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 250,278 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 110 |
ISO 3166 code | NG.OG.AS |
Ó ní ìwọ̀ ilẹ̀ tó tóbí tó 71 km2 àti èrò ènìyàn tó tó bíi 250,278 lásìkò ìkànìyàn ti ọdún 2006
Kóòù ìfìwéránṣe ti agbègbè náà ni 110.[1]
Aṣojú agbègbè náà tẹ́lẹ̀ rí ni Dimeji Bankole, tó jẹ́ agbẹnusọ fún ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin, láti ọdún 2003 wọ 2011.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)