Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ogbomosho

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ogbomosho South jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà. Olú ìlú Gúúsù Ògbómọ̀ṣọ́ wà ní agbègbè Arówómọlé ní ìlú Ògbómọ̀ṣọ́. Ó fẹ̀ ní ìwọ̀n 88km², ní ọdún 2006 wọ́n ka iye ènìyàn tí ó wà níbè sí 185,815.

Ogbomosho South
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilOyeniyi Timothy Oyedokun (PDP) Traditional ruler Onijeru of ijeruland
Time zoneUTC+1 (WAT)

Nọ́mbà ìfi lẹ́tà jíṣẹ́ sí ìlú náà ni 210.[1]

Ìjọba Ológun dá agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù Ògbómọ̀ṣọ́ sílẹ̀ ní ọdún 1991 láti ara ìjọba ìbílẹ̀ Ògbómọ̀ṣọ́ tẹ́lẹ̀. Àwọn ìlú tí ó yí ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù Ògbómọ̀ṣọ́ ni Idi- igba, Gaa- Lagbedu, Kajola, Kowe, Oke- Ola, Adeoye, Onidewure, Molete, Arowomole, Sanuaje, Obandi, Ijeru, Ayegun, and Oke Alapata.[2]

Àwọn Ibi tó gbajúmọ̀

àtúnṣe

State Hospital Complex – Sodiq Sekendegbe Street, Arowomole

Secretariat Complex – Arowomole

The Apostolic Church, Alapata Assembly[3]

National Museum, Arowomole

Nigerian Baptist Theological Seminary

Beulah Baptist Centre

State Library – Arowomole

Federal Housing Estate – Ibapon Road

Industrial Estate – Osogbo Road

Idi-Oro Baptist Church

Akande Market – Caretaker

DAD Foundation Sports Arena, Idi-Oro

Federal Road Safety Corps – Oluwatedo

Maryland Catholic High School

Methodist Cathedral – Arowomole

Berean Independent Baptist Church – Kajola

St Anne Catholic Church – Arinkinkin

St Ferdinand Catholic Church

Onpetu of Ijeru Palace

Government Technical college, Kajola

Baptist Secondary Grammar School, Ahoyaya.

The Apostolic Primary School II

Abede Primary School[2]

The Apostolic Model School

Aarada Market – Osogbo Road

Ayegun Primary School II

A.U.D Primary School, Awoye Street.

Kajola Primary School

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on November 26, 2012. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 "OGBOMOSO SOUTH LOCAL GOVERNMENT – Oyo State Government" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-05. 
  3. "The Apostolic Church Nigeria, Alapata Assembly, Ogbomoso. 🇳🇬 - WorldPlaces". nigeria.worldplaces.me (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-05.