Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilesa
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Ilaorun Ilesha)
Ìlà Oòrùn Iléṣà jẹ́ agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní Naijiria. Olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ náà wà ní Iyemogun ni ìlú Ilésà. Agbègbè náà tóbi tó 71 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 106,586 nígbà ìkànìyàn ọdún 2006. Kóòdù ìfìwéránṣé agbègbè yí sì jẹ́ 233.[1]
Ilesa East | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Osun State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Lanre Balogun |
Area | |
• Total | 71 km2 (27 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 106,586 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 233 |
ISO 3166 code | NG.OS.IH |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |