Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìrẹ́pọ̀

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Irepo)

Ìrépò jé agbègbè ìjoba ìbílè ní ìpínlè òyó ní orílè èdè Nàìjíríà. Àwon olú ìlú rè wa ni ìlú Kìsí.Ò nì agbègbè tí ó tó 984km² àti iye ènìyàn tí ó tó 122,553 níye níbí ònkà ènìyàn tí odún 2006 km2.

Irepo
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilSulaiman Lateef Adediran (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Orúko Oba ìlú kìsí ni ìjoba ìbílè agbègbè ìrépò ni IBA ti ìlú kìsí. Orúko IBA ti ìlú kìsí ni Oba Moshood Oyèkólá Àwèdá Lawal Arówóduye kejì.

Àmì òrò ìfilétá ránsé ti agbègbè náà ni 212. [1]

Àwon ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)