Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn Ṣakí

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ìjọba-Ìbílẹ̀ Ìwọòòrùn Ṣakí jẹ́ àgbègbè ìjọba-ìbílẹ̀ ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ṣakí ní ibùjókòó rẹ̀. Ìlú Ṣakí wà ní ìpẹ̀kun Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ibẹ̀ ni ibùdó center of Ẹkùn ìdigun kejì àwọn ọmọoogun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Ilé Ẹ̀kọ́ Gbogboǹṣe(TOPS), Ilé Ẹ̀kọ́ Ìkọ́ni-mọ̀ọ́ṣe, Ìlé Èkó Ológun. Ṣakí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí ó tóbi jùlọ ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Saki West
Nickname(s): 
Ìjọba
Ìlú Nàìjíríà
Ìpínlẹ̀Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Government
 • Alága Ìbílẹ̀Sarafadeen Omídìran (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ó ní ìwọ̀n ìbùsọ̀ bíi kìlómítà 2, 014km² àti òǹkà-ọ̀pọ̀nìyàn tí ó jẹ́ 278,002 nínú ètò-ìkànìyàn tí ọdún 2006.

Àmì nọ́mbà ìfìwèránńṣẹ́ rẹ́ ni 203.[1]

Àwọn abúlé àtúnṣe

Nomba iforukosile moto bere pelu: SHK[2][3]

Amioro ifiletaranse: 203[4]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2012-11-26. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. OYO STATE MOTOR VEHICLE IDENTIFICATION CODE NUMBERS[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2010-11-06. Retrieved 2009-12-23. 
  4. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Retrieved 2009-10-20. 

Àdàkọ:Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́