Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Obafemi-Owode

Obafemi Owode jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, tí a ṣẹ̀dá lẹ́yìn òfin No.9 of 1976, èyí tí ó jé áyorísi tí òfin ìjọba ìbílẹ̀ tí ọdún 1976. Síwájú ákoko yìí, ètò òṣèlú agbègbè yìí wá ní abẹ́ ìṣàkóso àṣẹ ìletò Owódé àti ìletò Obafemi.

Owode
Owode Egba
Aṣàfihàn agbègbè tí ilé-ìwé fi tọrẹ fún agbègbè yìí
Aṣàfihàn agbègbè tí ilé-ìwé fi tọrẹ fún agbègbè yìí
Owode is located in Nigeria
Owode
Owode
Location in Nigeria
Coordinates: 6°57′N 3°30′E / 6.950°N 3.500°E / 6.950; 3.500Coordinates: 6°57′N 3°30′E / 6.950°N 3.500°E / 6.950; 3.500
CountryNigeria
StateOgun State
Government
 • Local Government ChairmanAdesina Ogunsola (APC)
Area
 • Total1,410 km2 (540 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total228,851
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
110[1]
Area code(s)110106
ISO 3166 codeNG.OG.OO
Lua error in Module:Mapframe at line 289: attempt to perform arithmetic on local 'lat_d' (a nil value).

Àwọn ìtọ́kasi àtúnṣe

  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on October 7, 2009. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. gsc.og.gov.ng/obafemi-owode-local-govt/