Agodi Gardens (èdè Yoruba: Ọgbà Agodi) jẹ́ ọgbà kan tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Àwọn ènìyàn tún mọ̀ ọ́ sí Agodi Botanical Gardens, Agodi Gardens, Ibadan, ọgbà náà gba ilẹ̀ tí ó tó 150 acres.[2][3]

Ìtàn àtúnṣe

Orúkọ ọgbà náà tẹ́lẹ̀ ni Agodi Zoological and Botanical Gardens, wọ́n dá Agodi Gardens kalẹ̀ ní ọdún 1967. Ìkún omi Ogunpa tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1980 ba ọgbà náà jẹ́, ó sì gbé ọ̀pọ̀ àwọn ẹranko ọgbà náà lọ. Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sì tún ọgbà náà ṣe ní ọdún 2012, wọ́n sì tun sí ní ọgbà Agodi ní ọdún 2014.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Okereke, Dominic (2012). Africa's Quiet Revolution Observed from Nigeria. Paragon Publishing. p. 504. ISBN 978-1-908-3418-77. https://books.google.com/books?id=kFmU3i6d6PsC&pg=PA504. Àdàkọ:Self-published source
  2. Oladele, Bisi (September 10, 2014). "Life Returns to Agodi Gardens". The Nation. http://thenationonlineng.net/life-returns-to-agodi-gardens/. Retrieved July 11, 2016. 
  3. Busari, Tunde (June 20, 2015). "Ibadan Returns to Good Old Days with Agodi Resort". Newswatch Times. http://www.mynewswatchtimesng.com/ibadan-returns-to-good-old-days-with-agodi-resort/. Retrieved July 11, 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. Obuekwe, Chiamaka (28 June 2017). "Review of Agodi Gardens". The Guardian (Nigeria). Archived from the original on 17 April 2018. https://web.archive.org/web/20180417024513/https://m.guardian.ng/life/travel-and-places/review-of-agodi-gardens/. Retrieved 16 April 2018.