Agony of Christ jẹ́ fíìmù Ghana tó jáde ní ọdún 2009, tí Frank Rajah Arase darí.[1]

Agony Of Christ
AdaríFrank Rajah Arase
Olùgbékalẹ̀Abdul Salam Mumuni
Òǹkọ̀wéAbdul Salam Mumuni
Ilé-iṣẹ́ fíìmùVenus Films Production
Déètì àgbéjáde
  • 2009 (2009)
Orílẹ̀-èdèGhana
ÈdèEnglish

Àhunpọ̀ ìtàn

àtúnṣe

Arákùnrin kan sá kúrò ní ìlú rẹ̀ nítorí ìyá-aláwo ìlú náà fẹ́ pa á. Àwọn ẹlésìn Kìrìsìtẹ́ẹ̀nì kan ló kó o yọ, tí wọ́n sì tọ sọ́nà láti mọ ẹ̀sìn náà, tí ó fi di àtúnbí. Ó padà sí ìlú rẹ̀, níbi tí wọ́n ti ń sin àwọn òòṣà kékèèké. Ó gbìyànjù láti yí ọkàn àwọn ará-ìlú náà pada, àmọ́ ìyá-aláwo ìlú náà ò fi àyè gbà á, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní gbógun ti arákùnrin yìí.[2]

Àwọn òṣèré tó kópa

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. nollywoodreinvented (2012-11-02). "Agony of the Christ". Nollywood Reinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-29. 
  2. Francis Addo, Francis. "Agony Of The Christ' Premiered". Modern Ghana. Francis Addo. Retrieved 8 November 2018.