Ahmed Mohamed Mohamoud
Ahmed Mohamed Mohamoud "Silanyo" (Àdàkọ:Lang-so, Lárúbáwá: احمد محمد محمود سيلانيو; tí a bí ní ọdún 1938) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Somalila, òun ni ààrẹ tí ó dárí Somalia láàrin ọdún 2010 sí 2017. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ mínísítà fún ètò ọrọ̀ ajé Somali Republic, ó sì ti di àwọn ipò mìíràn mú ní ìjọba. Oun ní o jẹ́ alága Somali National Movement nígbà àwọn ọdún 1980s.[3]
A yàn án gẹ́gẹ́ bí ààrẹ orílẹ̀ èdè Somalia ní ọdún 2010.[4] Ahmed ní ààrẹ kẹrin láti gun orí àléfà ìjọba orílẹ̀ èdè Somalia.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ministry of Finance of Somaliland - Former Ministers". Ministry of Finance (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ 37. Somalia/Somaliland (1960-present). https://uca.edu/politicalscience/dadm-project/sub-saharan-africa-region/somaliasomaliland-1960-present/.
- ↑ "Somaliland Election Results Released: Siilaanyo Is New President". Bridge Business Magazine. 3 August 2010.
- ↑ "Opposition leader elected Somaliland president". AFP. https://www.google.com/hostednews/afp/article/ALeqM5j8hma5FaM4Jn8UUVlRwwK18hpStQ.