Muse Bihi Abdi
Musa Bihi Abdi (Àdàkọ:Lang-so, Lárúbáwá: موسى بيحي عبدي; tí a bí ní ọjọ́ 1948)[2] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Somalia, òun ni ààre orílẹ̀ èdè Somalia láti oṣù kẹwàá ọdún 2017. Nígbà 1970s, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi awa ọkọ̀ ojú òfuurufú fún àwọn ọmọ ológun òfuurufú Somalia lábé ìdarí Siad Barre. Ní ọdún 2010, a yan Bihi sípò alága ẹgbẹ́ òṣèlú Kulmiye ti Republic of Somaliland. Ní oṣù kọkànlá ọdún 2015, a tún yan Bihi gẹ́gẹ́ bi ẹni tí yóò du ipò ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú náà.[3][4]
Muse Bihi Abdi | |
---|---|
موسى بيحي عبدي | |
Official portrait, 2017 | |
5th President of Somaliland | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 13 December 2017 | |
Vice President | Abdirahman Saylici |
Asíwájú | Ahmed Mohamed Mohamoud |
Chairman of Peace, Unity, and Development Party | |
In office 31 December 2010 – 21 August 2023 [1] | |
Asíwájú | Ahmed Mohamed Mohamoud |
Arọ́pò | shuaib hassan adan |
Minister of Interior | |
In office 1993–1995 | |
Ààrẹ | Muhammad Haji Ibrahim Egal |
Asíwájú | Suleiman Mohamoud Adan |
Arọ́pò | Ahmed Jaambiir Suldan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1948 (ọmọ ọdún 75–76) Hargeisa, British Somaliland |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Somalilander |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peace, Unity, and Development Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Zahra Abdilahi Absia Roda Ahmed Omar |
Àwọn ọmọ | 7 |
Alma mater | University of Hargeisa |
Signature |
Ní ọjọ́ kànlélógún oṣù kọkànlá ọdún 2017, a kéde Muse Bihi gẹ́gẹ́ bi ẹni tó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ orílẹ̀ èdè Somalia ti ọdún 2017. Ó di ààrẹ Somalia ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Kejìlá ọdún 2017.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Burco: Xiabiga Kulmiye oo mar kale musharax Madaxweyne u doortey Biixi". 21 August 2023.
- ↑ Olad, Mohamed (21 November 2017). "Somaliland Ruling Party Candidate Bihi Wins Election". Voanews.com. Retrieved 8 December 2017.
- ↑ "Somalia: Wrangle splits Somaliland Ruling Party as President Siilaanyo seeks re-election". 26 May 2014. http://allafrica.com/stories/201405270406.html.
- ↑ "Muse Bihi and Saylici Elected as Kulmiye's Presidential Candidate". 11 November 2015. Archived from the original on 28 January 2016. https://web.archive.org/web/20160128022439/http://galgalanews.com/articles/182/Somaliland-Muse-Bihi-and-Saylici-Elected-as-Kulmiyes-Presidential-Candidate.
- ↑ Olad, Mohamed. "Somaliland Ruling Party Candidate Bihi Wins Election" (in en). VOA. https://www.voanews.com/a/somaliland-ruling-party-candidate-bihi-wins-election/4128446.html.
- ↑ "PRESIDENT BIHI REPLACES HEADS OF MULTIPLE FOREIGN MISSIONS". Somaliland Chronicle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 November 2019. Retrieved 14 March 2020.