Aliyu Modibbo Umar

Olóṣèlú

Aliyu Modibbo Umar[1] (15 November, 1958) je oloselu omo ile Naijiria to di Alakoso Eto Agbara ati Irinlile labe ijoba Aare Olusegun Obasanjo ni 23 May[2],[3] 2003; Alakoso Eto Oro-aje ni July 2006 titi de July 2007 ati Alakoso Agbegbe Oluilu Apapo ile Naijiria titi de October 2008.

Aliyu Modibbo Umar
Minister of Power and Steel
In office
January 2003 – May 2003
Minister of Commerce
In office
July 2006 – July 2007
Minister for the Federal Capital Territory
In office
July 2007 – October 2008
AsíwájúNasir Ahmad el-Rufai
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 November, 1958
Gombe State, Nigeria


  1. Okonkwo, Oge (2015-02-12). "Aliyu Modibbo: Religious leaders criticised by former FCT minister". Pulse.ng. Retrieved 2018-07-02. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. Umar, Aliyu Modibbo (2013). Sahara Reporters http://saharareporters.com/2013/02/28/banana-invasion-aliyu-modibbo-umar.  Missing or empty |title= (help)
  3. "The Tilapia From China, By Aliyu Modibbo Umar". Premium Times Nigeria. 2013-04-23. Retrieved 2018-07-02.