Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà

(Àtúnjúwe láti Aare ile Naijiria)

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà (President of the Federal Republic of Nigeria) tàbì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lásán ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà náà tún ni Aláṣẹ pátápátá àwọn ológun Nàìjíríà. Àwọn ará Nàìjíríà ún dìbò yan ààrẹ fún ọdún mẹ́rin. Àwọn ipò ààrẹ, àwọn agbára, àti àwọn oyè olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba jẹ́ dídàpọ̀ sí ipò ààrẹ lábẹ́ Òfin-Ibágbépọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà odún 1979. Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, Bola Tinubu, bọ́ sí orí àga ní May 29, 2023, gẹ́gẹ́bí ààrẹ 16k Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.[3]

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà
President of the Federal Republic of Nigeria
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Bola Tinubu

since May 29, 2023
Executive Branch of the Federal Government
StyleMr. President
His Excellency
Member ofFederal Executive Council
National Security Council
ResidenceAso Villa
SeatAbuja, F.C.T.
AppointerDirect popular election
Iye ìgbàFour years, renewable once
Constituting instrumentÒfin-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà
Ẹni àkọ́kọ́Nnamdi Azikiwe
FormationÀdàkọ:Date and age
DeputyVice President of Nigeria
Owó osù14,000,000 annually[1]
Websitestatehouse.gov.ng
Former standard of the President
Flag of the President as Commander in Chief of the Nigerian Armed Forces

Nigbati Naijiria di ile apapo oselu olominira ni odun 1963 larin Awon Orile-ede Ajoni, o diwo mo ona ijoba igbimo asofin ti o jogun lat'owo ile Britani. Nnamdi Azikiwe ti o je Gomina Agba nigbana di Aare,[4] ipo to je fun ayeye, nigbati ti Abubakar Tafawa Balewa si di ipo Alakoso Agba mu.[4]

Àkójọ àwọn Olórí Ìjọba Ológun àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Ọdún 1963-1966

àtúnṣe

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1963-1966)

àtúnṣe
Oruko Ojoibi-Ojoalaisi Igba ijoba bere Igba ijoba pari Egbe oloselu
Nnamdi Azikiwe 1904 - 1996 1 October 1963 16 January 1966 (deposed) NCNC

Àwọn Olórí Ìjọba Ológun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1966-1979)

àtúnṣe

Àdàkọ:Oselu ni Naijiria

Oruko Ojoibi-Ojoalaisi Igba ijoba bere Igba ijoba pari Egbe oloselu
Ogagun Agba Johnson Aguiyi-Ironsi 1924 - 1966 16 January 1966 29 July 1966 (deposed and murdered Ologun
Ogagun Yakubu Gowon 1934 - 1 August 1966 29 July 1975 (deposed) Ologun
Ogagun Murtala Mohammed 1938 - 1976 29 July 1975 13 February 1976 (assassinated) Ologun
Ogagun Olusegun Obasanjo (1st time) 1937 - 13 February 1976 1 October 1979 Ologun

Ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà (1979-1983)

àtúnṣe
Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Shehu Shagari 1925 - 2018 1 October 1979 31 December 1983 (deposed) NPN

Alaga Igbimo Ologun Togajulo ile Naijiria (1983-1985)

àtúnṣe
Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Muhammadu Buhari 1942 - 31 December 1983 August 27 1985 (deposed) Ologun

Aare Igbimo Ile-ise Ologun ile Naijiria (1985-1993)

àtúnṣe
Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
General Ibrahim Babangida 1941 - 27 August 1985 26 August 1993 (resigned) Ologun

Olórí orílẹ̀-èdè ìjọba fìdíhẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (1993)

àtúnṣe
Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Ernest Adegunle Oladeinde Shonekan 1936 - 26 August 1993 17 November 1993 (deposed) Koni

Alaga Igbimo Ijoba Igba Pato ile Naijiria (1993-1999)

àtúnṣe
Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
General Sani Abacha 1943 - 1998 17 November 1993 8 June 1997 (died in office) Ologun
General Abdulsalami Abubakar 1942 - 8 June 1998 29 May 1999 Ologun

Àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (1999-Oni)

àtúnṣe
Ọrúkọ Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí Ìgbà bẹ̀rẹ̀ Ìgbà parí Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Olusegun Obasanjo (2nd time) 1937 - 29 May 1999 29 May 2007 PDP
Umaru Yar'Adua 1951 - 2010 29 May 2007 5 May 2010 (died in office) PDP
Goodluck Jonathan 1957 - 5 May 2010 29 May 2015 PDP
Muhammadu Buhari 1942- 29 May 2015 29 May 2023 APC
Bola Tinubu 1952- 29 May 2023 APC  1. Ibeh, Nnenna (30 May 2015). "Buhari to earn N14 million as annual salary, allowances". Premium Times. http://www.premiumtimesng.com/news/headlines/184046-buhari-to-earn-n14-million-as-annual-salary-allowances.html. 
  2. Orjinmo, Nduka (2022-06-08). "Bola Tinubu - the 'godfather' who has been sworn in as Nigeria's president". BBC News. Retrieved 2023-06-12. 
  3. "Bola Tinubu". Encyclopedia Britannica. 2023-03-15. Retrieved 2023-06-12. 
  4. 4.0 4.1 "Nnamdi Azikiwe - Biography & Facts". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2023-06-12.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Encyclopedia Britannica 1998" defined multiple times with different content

E tun wo

àtúnṣe