Annabella Zwyndila

Òṣéré orí ìtàgé

Annabella Zwyndila jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ káàkiri gẹ́gẹ́ bi Ms Green.

Annabella Zwyndila
Annabella Zwyndila photo shoot
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Kọkànlá 1992 (1992-11-21) (ọmọ ọdún 32)
Ibadan, Oyo, Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Jos
Iṣẹ́Actress, model, singer
Ìgbà iṣẹ́2012—present
AwardsZAFAA Awards as Best Upcoming Actress

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Annabella Zwyndilàilú Ìbàdàn, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ òṣíṣẹ́ àgbà nídi ṣíṣe ètò ẹ̀kọ́ àwọn ará ìlú. Ó lọ sí ilé-ìwé Command Secondary School ní ìlú Jos, Ìpínlẹ̀ Plateau ṣááju kí ó tó lọ sí Yunifásitì ìlú Jos níbití ó ti gba oyè ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ eré ìtàgé ṣíṣe.

Àkójọ àwọn eré tí ó ti kópa

àtúnṣe
Àkọ́lé Ipa Ọdún
Samantha Samantha 2012
Twisted Union Chantel 2013
Free to Live (Super Story) Turai 2017
RedBox Queen Shagbo 2017
New Jerusalem Charity
Last Men Of New Jerusalem Charity
Painful Sin 2010
Common Grounds Ann 2012
Mario Mario 2014
Amstel Malta Box Office (AMBO 3) Reality Show 2007

Àwọn ìyẹ́sí

àtúnṣe
  • ZAFAA Awards as Best Upcoming Actress[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe