Ahmed Ololade tí wọ́n bí ni ojó kankànlá oṣú kẹfà, ọdún 1995, tí orúkọ ìnágìjẹ rẹ̀ ǹjè Asake jẹ́ olórin Afrobeats láti orílẹ́ èdè Nàìjíríà.[1] Ójẹ́ olórin lábẹ́ àkóso YBNL Nation.[2]

Iṣẹ́ àtúnṣe

Asake kẹ́kọ̀ọ́ Theatre & Performing arts ní Obafemi Awolowo University, Ile-Ife, Osun state. Iṣẹ orin rẹ di gbajumọ ni ọdun 2020, nigbati o se àgbéjáde ere ọfẹ kan ti akole rẹ̀ jẹ́ 'Mr Money'.

Awọn itọkasi àtúnṣe