Aserbaijan Ní ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ́ mílíọ̀nù méjè àbọ̀. Òun ni ó jẹ́ èdè ìjọba fún Aserbaijani níbi tí àwọn ìdá mẹ́ta nínú mẹ́rin àwọn tí ó ń gbé ibẹ̀ ti ń sọ ọ́. Àwọn ìdá mẹ́fà nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé Rọ́sía ni ó ń sọ èdè yìí. Àwọn èdè bú méjìlà mìíràn tún wà èyí tí Avar àti Armerican wà lára wọn.

Orile ede Aserbaijan

Azərbaycan Respublikası
Flag of Aserbaijan
Àsìá
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Aserbaijan
Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto: none
Orin ìyìn: Azərbaycan Respublikasının Dövlət Himni
(March of Azerbaijan)
Location of Aserbaijan
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Baku
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaÈdè Aserbaijani
Orúkọ aráàlúAzerbaijani
ÌjọbaPresidential republic
• Aare
Ilham Aliyev (İlham Əliyev)
Mehriban Aliyeva (Mehriban Əliyeva)
Ali Asadov (Əli Əsədov)
Olominira 
from the Soviet Union
• Declared
August 30 1991
• Completed
October 18 1991
Ìtóbi
• Total
86,600 km2 (33,400 sq mi) (114th)
• Omi (%)
1.6%
Alábùgbé
• 2018 estimate
9,937,448[1] (91th)
• 2002 census
8,265,000
• Ìdìmọ́ra
113/km2 (292.7/sq mi) (99th)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$94.318 billion[2] (77th)
• Per capita
$10.340[2] (96th)
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$72.189 billion[2] (85th)
• Per capita
$7,914[2] (78th)
Gini (2006)36.5
medium · 58th
HDI (2007) 0.746
Error: Invalid HDI value · 98th
OwónínáManat (AZN)
Ibi àkókòUTC+4
Àmì tẹlifóònù994
Internet TLD.azItokasi àtúnṣe