Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà
Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà (pípè /ˈbɒzni.ə (ænd) hɜrtsɨˈɡoʊvɨnə/ ( listen)[5] or /ˌhɜrtsɨɡoʊˈviːnə/;[6] Bosnian, Croatian, Serbian Latin: Bosna i Hercegovina; Bosnian and Serbian Cyrillic: Босна и Херцеговина) je orile-ede ni Guu-Apailaorun Europe, ni Peninsula Balkani. O ni bode mo Kroatia ni ariwa, iwoorun ati guusu, Serbia ni ilaorun, ati Montenegro si guusuilaorun, Bosnia ati Herzegovina (bakanna: Bosnia-Herzegovina/Bosnia ati Hercegovina) je ku di ko je ayikanule, ayafi fun 26 kilometres (16 miles) ebado Omi-okun Adriatiki, ni ilu Neum.[7][8] Abenu orile-ede na je kiki okegiga ni arin ati si guusu, ilegiga ni ariwaiwoorun, ati ile pelebe ni ariwa ilaorun. Ninu na tu ni ibi jeografi totobiju to ni ojuojo orile iloworo, to ni igba orun gbigbona ati igba otutu to ni yinyin. Eti apaguusu re ni ojuojo Mediteraneani ati ojuile pelebe.
Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà Bosnia and Herzegovina Bosna i Hercegovina Босна и Херцеговина | |
---|---|
Orin ìyìn: Državna himna Bosne i Hercegovine The National Anthem of Bosnia and Herzegovina | |
![]() Ibùdó ilẹ̀ Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà (green) on the European continent (dark grey) — [Legend] | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | ![]() |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Bosnian/Croatian/Serbian[1] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 48% Bosniak 37% Serb 14% Croat[2] |
Orúkọ aráàlú | Bosnians, Herzegovinians |
Ìjọba | Parliamentary republic[3] |
Valentin Inzko1 | |
Haris Silajdžić2 Nebojša Radmanović3 Željko Komšić4 | |
Nikola Špirić | |
Independence | |
• Formed | August 29, 1189 |
• Banate established | 1154 |
1527 | |
1908 | |
• National Day | November 25, 1943 (establishing of the anti-fascist governing organ ZAVNOBIH) |
• Independence Day (from the SFR Yugoslavia) | March 1, 1992 |
• Observed | April 6, 1992 |
Ìtóbi | |
• Total | 51,129 km2 (19,741 sq mi) (127th) |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 4,613,414[2] (120th5) |
• 1991 census | 4,377,053 |
• Ìdìmọ́ra | 902/km2 (2,336.2/sq mi) (126th5) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $29.477 billion[4] |
• Per capita | $7,361[4] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $17.133 billion[4] |
• Per capita | $4,278[4] |
Gini (2007) | 30.15 medium |
HDI (2008) | ▲ 0.812 Error: Invalid HDI value · 76th |
Owóníná | Convertible Mark (BAM) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 387 |
Internet TLD | .ba |
|
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
ItokasiÀtúnṣe
- ↑ There is a single official language of Bosnia and Herzegovina, which goes under three names. From the (1993) language law:
In the Republic of Bosnia and Herzegovina, the Ijekavian standard literary language of the three constitutive nations is officially used, designated by one of the three terms: Bosnian, Serbian, Croatian. Both alphabets, Latin and Cyrillic, are equal.
(Language in the former Yugoslav lands (2004) Ranko Bugarski, Celia Hawkesworth. p 142) - ↑ 2.0 2.1 Bosnia and Herzegovina – CIA World Factbook
- ↑ https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/bk.html
- ↑ 4.0 4.1 4.2 4.3 "Bosnia and Herzegovina". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.
- ↑ Àdàkọ:USdict
- ↑ "Bosnia and Herzegovina – Definition of Bosnia and Herzegovina at". Yourdictionary.com. Retrieved 2010-01-25.
- ↑ Field Listing – Coastline, The World Factbook, 2006-08-22
- ↑ Bosnia and Herzegovina: I: Introduction, Encarta, 2006. Archived 2009-10-31.