Olorunyomi Oloruntimilehin (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Kẹjọ ọdún 1999) tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ Bad Boy Timz jẹ́ olórin olórin ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kọ orin "MJ,"[1] àti àtúnkọ orin náà pẹ̀lú Mayorkun.

Bad Boy Timz
Background information
Orúkọ àbísọOlorunyomi Oloruntimilehin
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiBad Boy Timz
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹjọ 1999 (1999-08-13) (ọmọ ọdún 25)
Lagos
Irú orinAfrobeats
Occupation(s)
  • Songwriter
  • singer
InstrumentsVocals
Years active2019 – present
LabelsShock Absorbers Music
Associated acts

Olamide ṣàfihàn rẹ̀ nínú orin rẹ̀, tí í ṣe Loading off Carpe Diem[2], tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Rookie of the Year ní The Headies 2020.[3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ní ọdún 2019, àwọn orin àti ijó Bad Boy Timz tí àọn ènìyàn ń kan sárá sí bọ sí gbàgedè ojú-ìwòrán fún ilé-iṣẹ́ olórin kan, ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2019, wọ́n pè é kí ó wá tọwọ́ bọ ìwé àṣẹ pẹ̀lú wọn.[4]

Ní ọdún 2020, Bad Boy Timz kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní Bells University of Technology, pẹ̀lú oyè ẹ̀kọ́ nínú Computer Engineering.

Àtòjọ àwọn orin rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn orin àdákọ

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ìtọ́ka
2019 "Hustle"
"Complete Me" [6]
2020 "MJ"
"MJ Remix" (featuring Mayorkun) [7]
"Have Fun" [8]
"MJ Remix" (featuring Teni)
2021 "Move" [9]
“Oasis”
“Skelele” (featuring Olamide) [10]

Gẹ́gẹ́ bí i olórin tí wọ́n ṣàfihàn

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Olùgbéjáde Àwo-orin Ìtọ́ka
2020 "Loading"(Olamide) P.Prime Carpe Diem
2020 "Denge Pose" (Dandizzy) Rage
2021 "Complicationship"(Tanasha Donna) [11]
2022 "Faaji"(Blaqbonez|1da Banton)
2024 “Grace” (Donny Crown) [1]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ

àtúnṣe
Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀bùn Olùgbà Èsì Ref(s)
2020 City People Entertainment Awards Best New Act "Himself" rowspan=2 Gbàá [12]
The Headies, The Rookies Rookie of the Year [13]
2021 Net Honours Most played Hip Hop song "Loading" (Olamide featuring Bad Boy Timz) Wọ́n pèé [14]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "10 Nigerian Artistes To Watch In 2021". 27 December 2020. Retrieved 28 April 2021. 
  2. "Bad Boy Timz". Retrieved 28 April 2021. 
  3. "How Bad Boy Timz Won The Award For Rookie Of The Year At Headies Explore". 22 February 2021. Retrieved 16 March 2021. 
  4. "As up-and-coming artiste, I attended events without performing –Bad Boy Timz". 28 March 2020. Retrieved 28 April 2021. 
  5. "Album: Timz EP by Bad Boy Timz". Retrieved 1 December 2021. 
  6. "Bad Boy Timz – "Complete Me"". 12 November 2019. Retrieved 3 January 2022. 
  7. "[Music] Bad Boy Timz Ft. Mayorkun – MJ (Remix)". 19 June 2020. Retrieved 3 January 2022. 
  8. "Bad Boy Timz – "Have Fun"". 6 November 2020. Retrieved 3 January 2022. 
  9. "New Music: Bad Boy Timz – Move". 24 October 2021. Retrieved 1 December 2021. 
  10. "Bad boy timz Skelele ft Olamide". 24 May 2021. Retrieved 3 January 2022. 
  11. "Complicationship (feat. Badboy Timz)". 30 October 2021. Retrieved 3 January 2022. 
  12. "Winners emerge at 2020 City People music awards". Citypeopleonline.com. 7 December 2020. 
  13. "The Headies 2021: Fireboy, Omah Lay, Bad Boy Timz win first-ever award [See list of winners]". 22 February 2021. Retrieved 28 April 2021. 
  14. "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07.