Dandizzy
Olórin ilẹ̀ Nàìjíríà
Daniel Tuotamuno Darius (tí wọ́n bí ní 6 October ọdún 1996), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Dandizzy, jẹ́ olórin ilẹ̀ Nàìjíríà àti akọrin sílẹ̀.[1][2]
Dandizzy | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Daniel Tuotamuno Darius |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2017–present |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeDandizzy jẹ́ ọmọ ìlú Opobo ní Port Harcourt, ní Ìpínlẹ̀ Rivers, Nàìjíríà.[3] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ ní ọdún 2009 gẹ́gẹ́ bíi ìràwọ̀ tó ń tàn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó di gbajúmọ̀ ní 22 January ọdún 2017. Ó tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Cadilly Entertainment, àmọ́ ó kúrò lẹ́yìn ọdún méjì. Ní oṣù August ọdún 2022, Regal Dry Gin fi ṣe aṣojú ilé-iṣẹ́ wọn.[4][5]
Àtọ̀jọ àwọn orin rẹ̀
àtúnṣe- Mbong ft. Bella Shmurda
- Sote ft. Falz[6][7]
- Denge Pose ft. Bad Boy Timz[8]
- Who Goes Der
- Woskey
- Money ft. Dice Ailes
- Yawa ft. Skales
- Bad Boy Szn[9]
Gẹ́gẹ́ bíi akọrin kejì
- Trust Issues (Mansa Coal feat Dandizzy)[10]
- Want (Rage feat. Dandizzy)
- Wida You Remix (Abobi Eddieroll feat. DanDizzy & Kayswitch)
- Trips & Munchies (Chimy feat. Dandizzy & Dr Barz)
- Wetin No Good (Idahams feat Eltee Skhillz, Dandizzy)
- Armageddon (DJ Joenel feat. Dandizzy, Dr Barz & Ajebo Hustlers)[11]
- For my Baby (Beekay feat. Angelika & DanDizzy)
- Miracle (King Jamal feat. DanDizzy, Dr Barz & Chockie)
- Logos Party (Logos Olori feat. DanDizzy)
- PH Confidential (Kaystyle feat. DanDizzy)
- Juggernaut (AKtheKING feat. DanDizzy)
- For You (Legendary Suni feat. DanDizzy)
- Loli (Da Chris feat. DanDizzy)
- Soft Play (DJ Blizz feat. DanDizzy)
- Burn (Angelika_belle feat. DanDizzy)
- I Pray (Pro-Mix feat. DanDizzy & Meyar)
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeYear | Event | Prize | Ref(s) |
---|---|---|---|
2018 | Galaxy Music Award | Best Rap single | |
Galaxy Music Award | Artist of the Year | ||
2019 | Galaxy Music Award | Artist of the Year | [12] |
Galaxy Music Award | Song Of The Year |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Nigerian rapper Dandizzy rallies people to vote". Africanews (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 May 2024.
- ↑ "Yhemo Lee Shares How He Helped Asake Meet Olamide and Secure a Record Deal -". The Herald (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 June 2023. Retrieved 30 May 2024.
- ↑ "Dandizzy And The UGLY Gems From Port Harcourt". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 13 April 2024. Retrieved 30 May 2024.
- ↑ Emmanuel, Stanley (August 2022). "Regal Gin unveils Dandizzy as brand ambassador". Retrieved 20 December 2023.
- ↑ Rapheal (4 August 2022). "Firm signs on Dandizzy as brand ambassador". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 May 2024.
- ↑ Emmanuel, Stanley (29 September 2023). "New Music: DanDizzy feat. Falz — Sote". Bella Naija. Retrieved 20 December 2023.
- ↑ "DanDizzy taps Falz for new single 'Sote'". NotJustOk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 29 September 2023. Retrieved 30 May 2024.
- ↑ "New Music: DanDizzy feat. Bad Boy Timz – Denge Pose". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 18 December 2020. Retrieved 30 May 2024.
- ↑ Adebiyi, Adeayo (12 October 2022). "Fast-rising rapper Dandizzy drops new hit single 'Bad Boy Szn'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 May 2024.
- ↑ "Mansa Cole out with brand new song ' Trust issues' featuring Dandizzy". www.vanguardngr.com.
- ↑ Emmanuel, Stanley (20 December 2023). "[Music] DJ Joenel – Armageddon ft. Ajebo Hustlers, Dr Barz & Dan Dizzy". TooXclusive. Retrieved 20 December 2023.
- ↑ "2019 Winners - The GMAs". 26 March 2023. Archived from the original on 26 March 2023. Retrieved 30 May 2024.