Bàrbúdà

(Àtúnjúwe láti Barbuda)

Barbuda je erekusu ni Apailaorun Karibeani, o si je apa orile-ede Antigua ati Barbuda. O ni olugbe to to bi 1,500, opo won ti won ungbe ni ilu Codrington.

Barbuda
Jẹ́ọ́gráfì
IbùdóCaribbean Sea
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn17°37′N 61°48′W / 17.617°N 61.800°W / 17.617; -61.800Coordinates: 17°37′N 61°48′W / 17.617°N 61.800°W / 17.617; -61.800
Àgbájọ erékùṣùLeeward Islands, Lesser Antilles
Ààlà160.56 km2 (61.993 sq mi)
Ibí tógajùlọ38 m (125 ft)
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀Highlands
Orílẹ̀-èdè
Antigua and Barbuda
Ìlú tótóbijùlọCodrington (pop. 1,252)
Demographics
Ìkún1,370
Ìsúnmọ́ra ìkún9.34 /km2 (24.19 /sq mi)

Barbuda budo si ariwa Antigua, larin awon Erekusu Leeward. Ni guusu re ni awon erekusu Montserrat ati Guadaloupe wa, ati ni ariwa ati iwoorun re ni Nevis, St. Kitts, St. Barts, ati St. Martin wa.