Bassey Albert Akpan
Olóṣèlú Nàìjíríà
Bassey Albert Akpan(tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kẹ̀wá ọdún 1972)[1] je olóṣèlú ní orílè-èdè Nàìjíríà, àti Senato ilé ìgbìmò asofin Nàìjíríà láti June 2015. Kí ó tó dé ipò náà, ó jé comisioner fún ètò Owó ni ìpínlè Akwa Ibom láti 2007 sí ọdun 2014.
Bassey Albert Akpan | |
---|---|
Senato ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti Akwa Ibom North-East Senatorial District | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 9 June 2015 | |
Asíwájú | Ita Enang |
Commissioner for Finance Akwa Ibom State, Nigeria | |
In office 7 August 2007 – 24 April 2014 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀wá 1972 Ibiono Ibom LGA, Akwa Ibom State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (Nigeria) (PDP) |
Website | senatoroba.org |
A kókó yàn sí ipò Senato ni oṣù kẹta ọdun 2015, láti se aṣojú agbègbè Akwa Ibom, a sì tún ti yàn sí ipò náà ní oṣù kejì ọdun 2019. Ó jé ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People Democratic Party Nàìjíríà.[2][3]
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Profile – Senator" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-03. Retrieved 2019-10-03.
- ↑ "Senate mulls mandatory computer education for teachers, pupils". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-17. Retrieved 2022-02-21.
- ↑ "SDP offers gov ticket to PDP senator in Akwa Ibom". thenationonlineng.net. Retrieved 2022-03-18.