Billie Jean
"Billie Jean" je orin ijo pop R&B latowo akorin omo ile Amerika Michael Jackson. Jackson lo ko siwe ti Quincy Jones si se atokun re fun awo orin Jackson to n je Thriller ni 1982. Lakoko Jones ko fi be feran re, die lo ku ko yokuro ninu awo orin na leyin ijiyan to ni pelu Jackson nipa re.
"Billie Jean" | ||||
---|---|---|---|---|
Single by Michael Jackson | ||||
from the album Thriller | ||||
B-side | "It's the Falling in Love"/"Can't Get Outta the Rain" | |||
Released | Oṣù Kínní 2, 1983 | |||
Format | 7" single 12" single | |||
Recorded | 1982 | |||
Genre | Dance-pop R&B Funk | |||
Length | 4:55 (album/single version) 6:22 (original 12" version) 2:20 (home demo version) | |||
Label | Epic Records | |||
Songwriter(s) | Michael Jackson | |||
Producer(s) | Michael Jackson, Quincy Jones | |||
Michael Jackson singles chronology | ||||
| ||||
|-
! colspan="3" scope="col" style="text-align: center; background:khaki;" | Thriller track listing |- | colspan="3" |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |