Quincy Jones
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America (1933–2024)
Quincy Delight Jones, Jr. ( March 14, 1933 -Oṣù Kọkànlá 3 ,2024) je ara ile Amerika to je alakoso orin, atokun awo orin, eleto orin, alasopo orin filmu, atokun telifisan, ati afonfere. Larin adota odun to fi sise ninu ise faaji, Jones gba idaloruko fun Ebun Grammy ni igba 79 to je eni akoko to gba eyi,[1] 27 awon Ebun Grammy,[1] ti Ebun Akikanju Grammy ni 1991 je ikan ninu won. O gbajumo gege bi atokun awo orin Thriller, ti Michael Jackson gbe jade ni 1982, eyi to ta iye to je 110 legbegberun kakiriaye,[2] ati atokun ati alakoso orin ore anu “We Are the World”.
Quincy Jones | |
---|---|
Quincy Jones, 2014 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Quincy Delight Jones, Jr. |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Leigh Warren |
Ọjọ́ìbí | Chicago, Illinois, U.S. | Oṣù Kẹta 14, 1933
Ìbẹ̀rẹ̀ | Seattle, Washington, U.S. |
Aláìsí | 2024 |
Irú orin | Pop, funk, soul, big band, swing, jazz, traditional pop, bossa nova, hip-hop |
Occupation(s) | Musician, conductor, producer, arranger, composer, film composer |
Instruments | Trumpet, drums, vocals, synthesizer |
Years active | 1951 – 2024 |
Labels | Columbia, Mercury, Qwest |
Associated acts | Michael Jackson, Frank Sinatra, Dinah Washington, Dean Martin, Patti Austin, Tevin Campbell, Marvin Gaye, Stevie Wonder, Will Smith |
Website | Official Quincy Jones Website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Callaway, Sue (2007-01-28). "Fortune test drives a Mercedes Maybach with Quincy Jones — February 5, 2007". Money.cnn.com. Retrieved 2009-07-18.
- ↑ "Jacko's Back! | MTV UK". Mtv.co.uk. 2006-11-16. Retrieved 2009-07-18.