Bimbo Manuel

Òṣéré orí ìtàgé

Bímbọ́ Manuel tí wọ́n bí ní ọgbọ̀njọ́ oṣù Kẹwàá Ọdún 1958. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé[1][2][3][4] tí wọ́n yàn án fún òṣèré tó peregedé jùlọ nínú amì-ẹ̀yẹ 2013 Nollywood Movies Awards ní ọdún 2013.

Bimbo Manuel
Ọjọ́ìbíọgbọ̀njọ́ oṣù Kẹwàá Ọdún 1958.
Ìpínlẹ̀ Èkó
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Port Harcourt
Iṣẹ́òṣèré orí-ìtàgé
Ìgbà iṣẹ́1986- di sin
Notable workBanana Island Ghost

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Bímbọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó [5]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akàròyìn ní orí ìkanì rédíò ti Ìpínlẹ̀ Ògùn (OGBC) , tí ó sì tún dara pọ̀ mọ́ Ilé-iṣẹ́ amóhù-máwòrán ti Ìpínlẹ̀ Ògùn (OGT) gègẹ́ bí akàròyìn bákan náà, lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀ Eré Oníṣẹ́ ti Tíátà, ní University of Port harcourt [6] before commencing his acting career in 1986[5]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe

Eré orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Actor Bimbo Manuel: 'It is not simple politics they play there at the AGN. It is filthy….'". stargist.com. Retrieved 13 August 2014. 
  2. "Nollywood needs to produce more quality films –Bimbo Manuel". thenationonlineng.net. Retrieved 13 August 2014. 
  3. "I was once paid N20 per show by NTA –Bimbo Manuel". dailyindependentnig.com. Archived from the original on 3 July 2014. Retrieved 13 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Nadia vs Manuel in Zero to Hero". punchng.com. Archived from the original on 22 August 2012. Retrieved 13 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. 5.0 5.1 "I have a good reputation-Bimbo Manuel". Nigerian Films. Archived from the original on December 24, 2014. Retrieved November 14, 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Segun Adebayo (May 19, 2013). "I count my success in my wife, children... —Bimbo Manuel". Nigerian Tribune. Archived from the original on December 14, 2014. https://web.archive.org/web/20141214104135/http://tribune.com.ng/news2013/index.php/en/component/k2/item/12282-i-count-my-success-in-my-wife-children-bimbo-manuel. 
  7. "Ayo Lijadu, Bimbo Manuel lead actors in Shijuwomi". The Nation. Ozolua Uhakheme. Retrieved 22 April 2015. 
  8. "Fast Rising Actress, Judith Audu, Veteran Actors Ayo Lijadu, Bimbo Manuel Storm Location for SHIJUWOMI". Shybell Media. Shybell Media News. Archived from the original on 26 May 2015. Retrieved 14 April 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "'Shijuwomi' Judith Audu, Ayo Lijadu and Bimbo Manuel star in new movie". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 10 April 2015. Retrieved 9 April 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. "Banana Island Ghost Full Cast". Uzomedia. Retrieved 2017-05-20. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]

Àwọn Ìtàkùn Ìjásóde

àtúnṣe


Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-film-actor-stub