Biola Adebayo
òṣèré orí ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjírírà
Biola Adebayo gbọ́ jẹ́ òṣèrébìnrin tí ó ṣeré nínú àwọn eré bi Jade's cross, Tori Owo àti àwọn eré mìíràn.[1] Òṣèrébìnrin náà, Eniola Badmus àti Banky W ṣe ìpòlongo nípa àwọn ọ̀nà láti kọjú ààrùn coronavirus nípa tí ààrùn náà ń jà fitafita ní Nàìjíríà, wọ́n rọ àwọn ènìyàn láti dúró sínú ilé àti láti lọ àwọn èlò ìfowọ́.[2]
Biola Adebayo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 23 December Ìpínlẹ̀ Èkó |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásitì ìlú Eko |
Iṣẹ́ | Nollywood actress, Producer, TV Presenter |
Ìgbà iṣẹ́ | 2002 - Present |
Olólùfẹ́ | Oluseyi |
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeBiola gba àmì-ẹ̀yẹ Master degree nínú ìmọ̀ Public Administration ní Yunifásítì ìlú Èkó.[3][4]
Àtòjọ àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré
àtúnṣe- Tori oro[5]
- Ike Kefa
- Omo Abore
- Jade's cross
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Online, Tribune (2021-04-16). "Blingz Awards has become most anticipated in Ibadan — Convener". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-06.
- ↑ "Coronavirus: Banky W, Eniola Badmus, Biola Adebayo urge calm". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-01. Retrieved 2022-08-06.
- ↑ "Nollywood Actress Biola Adebayo bags new award - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-06.
- ↑ Online, Tribune (2021-07-10). "Nollywood stars, Biola Adebayo, Mofe Jebutu, bag Master’s degrees". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-06.
- ↑ "Rotimi Salami, Peju Ogunmola others reunite in 'Tori Owo'". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-27. Retrieved 2022-08-06.