Oloye Bode Akindele (2 June 1933 - 29 June 2020) jẹ onimọran ile-iṣẹ orilẹ-ede Naijiria kan ati Parakoyi ti ilu Ibadanland, ti apapọ iye oro re to $ 1.19 bilionu, gẹgẹ bi iwadi ti Ventures Africa se ti won si gbe jade ni ọdun 2013 ninu iwe iroyin Daily Telegraph . [2] O je eni ikerindinlogun ti o lowo julo ni orile ede Naijiria gege bi BuzzNigeria ti se apejuwe. Akindele ni oludasile ati Alaga ti Madandola Group, onisowo oju-omi, ile ise ti o n se orisirisi ohun elo, ti olu-ile ise re wa ni United Kingdom.[3]

Bode Akindele
Ọjọ́ìbí(1933-06-02)Oṣù Kẹfà 2, 1933
Oyo, Nigeria
AláìsíJune 29, 2020(2020-06-29) (ọmọ ọdún 87)
Apapa, Lagos State, Nigeria
Iṣẹ́Olokun-Owo ti o lami laaka, oludari ile ise Madandola Group ati ti Fairgate Properties
Àwọn ọmọFolake Coker & Oladipo Akindele[1]
Parent(s)
  • Pa Joshua Laniyan Akindele
  • Rabiatu Adedigba
Websitemodandolagroups.com

Awọn itọkasi àtúnṣe