Boni Haruna

Olóṣèlú

Boni Haruna (ojoibi 12 June 1957) lo je Gomina fun Ipinle Adamawa ni orile-ede Nigeria lati 29 May 1999 titi di 29 May 2007. O je omo egbe oloselu People's Democratic Party (PDP).

Boni Haruna
Gomina Ipinle Adamawa
In office
29 May, 1999 – 29 May, 2007
AsíwájúA.G. Husseni
Arọ́pòMurtala Nyako
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí12 June 1957ItokasiÀtúnṣe