Bosede Bukola Afolabi
Bosede Bukola Afolabi jẹ́ Dókítà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ onímọ̀ nípa àìsàn ojú ara àwọn obìnrin, òjògbón àti adarí ẹ̀ka àwọn olóyún àti àwọn àìsàn ti ojú ara obìnrin ní ilé ìwòsàn ti Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó, Èkó, Nàìjíríà.[1] Òun tún ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti alága MRH (Maternal and Reproductive Health) Research Collective.[1]
Bosede Bukola Afolabi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | London, England |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Queen’s College Yaba, Obafemi Awolowo University, University of Nottingham |
Iṣẹ́ | Consultant Obstetrician, Gynaecologist & Professor |
Gbajúmọ̀ fún | Professor of Obstetrics and Gynaecology, Director of the Centre for Clinical Trials, Research and Implementation Science (CCTRIS) at the University of Lagos |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Vladimir Duthiers,"Nigerian doctor fighting killer blood disease". edition.cnn.com. 3 March 2017. Retrieved 8 December 2021.