Boutros Boutros-Ghali (Arabiki: بطرس بطرس غالي, Koptiki: Bουτρος Βουτρος-Γαλι) (ojoibi 14 November 1922) je ara ile Egypt to je diplomati to wa ni ipo gege bi Akowe Agba kefa Agbajo Iparapo awon Orile-ede (UN) lati January 1992 de December 1996. O je onimo eko ati Alakoso Oro Okere ile Egypti, Boutros Boutros-Ghali sakoso UN nigbati orisi idamu lagbaye, bi ituka Yugoslafia ati Ipaniyanrun Rwanda sele.

Boutros Boutros-Ghali
6th Secretary-General of the United Nations
In office
1 January 1992 – 31 December 1996
AsíwájúJavier Pérez de Cuéllar
Arọ́pòKofi Annan
Foreign Minister of Egypt
In office
1977–1991
Secretary-General of Francophonie
In office
1997–2002
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kọkànlá 1922 (1922-11-14) (ọmọ ọdún 102)
Cairo, Egypt
Ọmọorílẹ̀-èdèEgyptian
(Àwọn) olólùfẹ́Leia Maria Boutros-Ghali



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe