Ìkọ kedere

Busiswa
Busiswa
Orúkọ àbísọBusiswa Gqulu
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kọkànlá 1988 (1988-11-08) (ọmọ ọdún 36)
Mthatha, Ìlà-Oòrùn, South Africa
Irú orin
Occupation(s)
  • Olórin
  • Akọrin
  • Akéwì
Instrumentsbozza
Years activeỌdún 2008– títí di àsìkò yìí
Labels
Associated acts

Busiswa Gqulu (Bí ní ọjọ́ kẹ́jọ oṣù kẹwàá, Ọdún 1988) , wọ́n mọ orúkọ ọlọ́rọ̀ kan rẹ̀ sí Busiswa tàbí Busi, jẹ́ Olórin-Akọrin àti Akéwì South African. Wọ́n bi ní Mthatha, ìlà-oòrùn káàpù, South Africa,[1] Ó di ìlú mọ̀ọ́ ká fún ìbáṣepọ̀ lórí orin DJ Zinhle "Orúkọ mi ni", lẹ́yìn tó di mímọ lọ́dọ̀ Kalawa Jazmee's Ọ̀gá ilé-iṣẹ́ Oskido.[2]

Lẹ́yìn ìbáṣepọ̀ tó dán mọ́rán pẹ̀lú DJ Zinhle, Ó kọ àwọn orin tó gbajúmọ̀ bí; "Ngoku", "Lahla", àti wí pé ó kọrin nínu orin Bhizer tó gbajúmọ̀, "Gobisiqolo".[3] Ní ọjọ́ kẹ́jọ oṣù Kejìlá, Ọdún 2017, Ó gbé álíbọ̀mù àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde, Highly Flavoured, lẹ́yìn náà orin, "Bazoyenza". Ní gbogbo ìgbésí ayé rẹ̀, Gqulu ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ oyè. Ní ọdún 2014, wọ́n dárúkọ rẹ̀ ní Mail & Guardian 200 Young South Africans.[4]