Chike Frankie Edozien
Chike Frankie Edozien | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹfà 1970 |
Iṣẹ́ |
|
Organization | New York University |
Works | Notable Works |
Awards | List of awards |
[1]Chiké Frankie Edozien jẹ́ ònkọ̀wé àti oníṣẹ́ ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ati Amẹ́ríkà.[2] Òun ni adarí àgbà fún New York University, Accra, òun náà sì tún ni olùdarí fún New York University Journalism. Orisirisi àpilẹ̀kọ ni ó ma ń ke tí ó sì ń gbé jáde nínú àwọn ìwé-ìròyìnrẹ̀. Òun ni ó kọ ìwé Lives of Great Men, ní ọdún 2007, ó sì gba ẹ̀bùn amì-ẹ̀yẹ Lambda Literary Award fún iṣẹ́ rẹ̀ náà.[3] Wọ́n yan ìwé rẹ̀ 'Lives' fún amì-ẹ̀yẹ Randy Shilts Award àwọn ìwé àpilẹ̀kọ ní ọdún 2018, tí ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé Triangle gbé jáde.[4] Edozien ti fi ìwé rẹ̀ yí sọ̀rọ̀ lórí òmìnira, ìfaradà àti akitiyan tí ó ṣe àfihàn rẹ̀ nínú ìwé rẹ̀ ní orísirṣi ìpéjọ agbáyé pàá pàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè India.[5][6][7][8][9][10] sí orílẹ̀-èdè Australia[11] àti New Zealand[12]àti South Africa[13][14] àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà<[15] Ghana[16] àti orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.[17]
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì káàkiri àgbáyé bíi:
Yale University[18], New York University[19] , anchester Metropolitan University[20] ,lstu Jayanti College, Bangalore,[21] University of Delhi,[22] and moràti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
Ìwé ‘Lives’ ni ó jẹ́ ìwé tí ó ṣe àgbéyẹwò ìgbé ayé àwọn LGBTQ tí wọ́n jẹ́ ọkùnrin àti obìnrin tí eọ́n wà ní ilẹ̀ Adúláwọ káàkiti agbáyé. Wọ́n yan Edozien's "Shea Prince" fún amì-ẹ̀yẹ 2018 Gerald Kraak Human Rights Award àti "Last Night in Asaba" ni wọ́n ṣà yàn fún àmì-ẹ̀yẹ Gerald Kraak ní ọdún 2019, lára àwọn ìwé rẹ̀ tí ó tún gbayì ni ‘As You Like It’, tí ó mu gba àmì-ẹ̀yẹ Lambda award ní ọdún 2019.[23] .
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Frankie Edozien". NYU Journalism (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-03.
- ↑ "Review: Chike Frankie Edozien's Lives Of Great Men | Kanyinsola Olorunnisola". Brittle Paper. 2018-10-26. Retrieved 2020-06-03.
- ↑ "Lambda Literary awardees include Carmen Maria Machado, John Rechy, Keeanga-Yamahtta Taylor" Archived October 16, 2019, at the Wayback Machine.. Windy City Times, June 5, 2018.
- ↑ "The Randy Shilts Award for Gay Nonfiction". The Publishing Triangle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Frankie Edozien – Jaipur Literature Festival". jaipurliteraturefestival.org/ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-09-17. Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "The Hindu Lit for Life 2019 | How to write a memoir" – via YouTube. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Reading and discussion with author Chiké Frankie Edozien". indulgexpress.com. Retrieved 2020-06-16.
- ↑ Jan 15, Priya Menon | TNN |; 2019; Ist, 07:09. "Change in India on gay sex holds out hope for Nigerians | Chennai News". The Times of India (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "AKLF's Just Two Days Away & Here's What Is Keeping Us Excited | LBB". LBB, Kolkata (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Chike Frankie Edozien | Zee Jaipur Literature Festival". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Love, Life and Activism – Adelaide Festival". 2020.adelaidefestival.com.au (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Memoir gives voice to gay Nigeria". RNZ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-27. Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Frankie Chike Edozien". Abantu Books (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "What to look forward to at the Franschhoek Literary Festival". CapeTalk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Betty Irabor Chike Edozien – Ake Festival" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Two Readings with Chiké Frankie Edozien | Writers Project of Ghana". writersprojectghana.com. Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "JLF Colorado 2019 | Lives of Great Men". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Hall, Linsly-Chittenden; Haven, 102 See map 63 High Street New; Ct 06511 (2019-04-11). "Meet the author: Chiké Frankie Edozien". The MacMillan Center (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Salon Series: A Conversation with Frankie Edozien". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "LGBT History Month: Chike Frankie Edozien by Jennifer Makumbi". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ kjcjournal (2019-02-01). "Prof. Frankie Edozien from New York University addressed the Journalism students". Department of Journalism & Mass Communication | Kristu Jayanti College, Bangalore (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16.
- ↑ "Department Of Journalism, LSR" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-16 – via Facebook.Àdàkọ:Primary source inline
- ↑ "Frankie Edozien, JK Anowe, Megan Ross, Lilian Aujo Lead 19-Strong Shortlist for the Gerald Kraak Prize". Brittle Paper. 2019-04-03. Retrieved 2020-06-03.