Claude Lévi-Strauss (klod levi stʁos; 28, November, 1908 - 30, October, 2009) je onímọ̀ẹ̀dá-ènìyàn (anthropologist) ati onímọ̀ẹ̀yà-ènìyàn (ethnologist) ara ile Fransi, be si ni o je ikan ninu awon omowe pataki ni orundun 20un ti o se ifilole iro nipa structuralism.

Claude Lévi-Strauss
OrúkọClaude Lévi-Strauss
Ìbí(1908-11-28)28 Oṣù Kọkànlá 1908
Brussels, Belgium
Aláìsí30 October 2009(2009-10-30) (ọmọ ọdún 100)
Paris, France
Ìgbà20th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Structuralism
Ìjẹlógún ganganAnthropology
Society
Kinship
Linguistics
Àròwá pàtàkìStructuralism
Mythography
Culinary triangle
Bricolage


Itokasi àtúnṣe