Daddy Showkey
Daddy Showkey tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ John Odafe Asiemo tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Daddy Showkey jẹ́ gbajúmọ̀ Olórin Orílè-èdè Nàìjíríà. Irúfẹ́ orin tó ń kọ ni a mọ̀ sí ghetto dance. Ó gbajúmọ̀ ní Ajegunle, ní ọdún 1990 sí 1999. Orúkọ àbísọ rẹ̀ ni John Odafe Asiemo àmọ́, orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jé Daddy Showkey káàkiri gbogbo ghetto nígbà náà.[1][2][3] Ó wá láti ìlú Olomoro, ní apá Gúúsù Isoko, ní ìpínlẹ̀ Delta.[4]
Àwọn orin àdákọ rè
àtúnṣe- 1996 "Diana"
- 1991 "Fire Fire"
- 2011 "The Name"
- 2011 "The Chicken"
- 2011 "Sandra"
- 2011 "Young girl"
- 2011 "Ragga Hip hop"
- 2011 "Asiko"
- 2011 "Mayazeno"
- 2011 "Girl's cry"
- 2011 "What's gonna be gonna be"
- 2011 "Welcome"
- 2011 "Ghetto Soldier"
- 2011 "Jehovah"
- 2011 "Dancing scene"
- 2017 "One Day"
- 2017 "Shokey Again"[5][6]
Àwọn ìfọwọsí-ìwé rẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 2018, Daddy Showkey jẹ́ asojú fún ilé-iṣẹ́ Real Estate Management Revelation Property Group ní ipinle Eko.
Ó wà lára àwọn gbajúgbajà oṣèré bíi Alex Ekubo, Ikechukwu Ogbonna, Belindah Effah, Mary Lazarus àti Charles Inojie.[7]
Àwọn àwo-orin rẹ̀
àtúnṣe- 2011 "The Name"somebody call my name showckey
- 2011 "Welcome"
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Daddy Showkey: My Life on the streets". Vanguard News. Retrieved 25 October 2014.
- ↑ "Visit My House And You'll Know If Am Broke - Daddy Showkey -NG Trends". NG Trends. Retrieved 25 October 2014.
- ↑ "VIDEO INTERVIEW: The Second Coming of Daddy Showkey". Ng Tunes. Retrieved 25 October 2014.
- ↑ "40 Isoko People you must be Proud of in Lagos". Nigerian Voice. Retrieved 2021-07-06.
- ↑ "Daddy Showkey's Songs In 2018", web.waploaded.com
- ↑ "Daddy Showkey – Showkey Again (Prod. Phat Beatz)" Archived 2017-02-10 at the Wayback Machine., www.naijavibes.com
- ↑ "Alex Ekubo, Daddy Showkey, others turn Brand Ambassadors". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-10. Retrieved 2021-03-02.