Dayò Amúsà
Dayọ̀ Amúsà ni wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ Èkó tí ó jẹ ọmọ obìnrun àkọ́kọ́ nínú àwọn márùún nínú ẹbi rẹ̀. Bàbà rẹ̀ jé ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn nìgbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Èkó. Ó lọ sì ilé-ẹ̀kọ́ Mayflower ní ìlú Ìkẹ́nẹ́ tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ Food Science and Technology ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe Moshood Abíọ́lá Polytechnic ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 2002. Ọpọ̀ ẹeré rẹ̀ tí ó ti kópa jùlọ ní eré orí ìtàgé èdè Yorùbá. Òun ni olùdásìlẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ PayDab tí ó pé méjì nílù Ìbàdàn àti Èkó. [1]
Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣe- Nollywood Female Face Of The Year 2017 Pink Awards
- Best Actress Indigenous Nollywood Movies Awards 2014
- Best Kiss In A Movie BON Awards 2013
- Best Crossover Act YMAA 2014
Outstanding Performance 2010
- The Ambassador Club
Outstanding Achievers Awards 2011 * Diamond Special Recorgnition Awards 2014
- Merit Awards 2013 J15 Schiool Of Art
- Achievers Award Of Honour J-KRUE 2013
- Award Of Excellence 2016 AFamily.[2]
Àwọn eré rẹ̀ tó ti kópa
àtúnṣe- AJÈGBODÒ 2006
- OJÚ OWÓ 2007
- ẸKAN ṢOṢO2008
- ÒÓGÙN MI 2009
- DÉWÙNMÍ ÌBẸ̀RẸÙ 2010
- INÚ
- IDAA 2012
- ARỌ́BA 2012
- UNFORGIVABLE 2015
- PATHETIC 2017
- OMONIYUN.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adesoji, Adetutu (2018-10-12). "What good sex means to a woman - Dayo Amusa". Vanguard News Nigeria. Retrieved 2019-03-14.
- ↑ "Dayo Amusa Biography, Age, Family, Married, Twin Sister, Songs and Movies". Informationcradle. 2017-07-13. Retrieved 2019-03-14.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]