Dayo Amusa (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù keje ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,[1][2][3][4][5] tí ó sì tún jẹ́ oludari ere ori itage.

Dayo Amusa
Ọjọ́ìbíTemidayo Amusa
20 Oṣù Keje 1983 (1983-07-20) (ọmọ ọdún 40)
Eko,Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaMoshood Abiola Polytechnic
Iṣẹ́
  • òṣèrébìnrin
  • Olorin
  • Oludari
Ìgbà iṣẹ́2002–present
Notable workAye Mii

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ àtúnṣe

Wọ́n bí Dayo Amusa lọ́jọ́ kedógún oṣù Keje ọdún 1983 si ilu Èkó. Dayo jẹ́ akobi ninu ọmọ tí àwọn òbí rẹ̀ bí.Ò lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Mayflower School ní ìlú Ikene.Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òunje ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti Moshood Abiola Polytechnic.

Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ àtúnṣe

Year Award Category Result Ref
2013 Best of Nollywood Awards Best Kiss In A Movie Gbàá
2014 Yoruba Movie Academy Awards Best Crossover Act Gbàá
2018 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Lead Role - Yoruba Wọ́n pèé [6]
2019 Wọ́n pèé [7]

Àwọn Orin Rẹ̀ àtúnṣe

  • Aye Mii
  • Ayemi Remix ft Oritsefemi
  • Alejo
  • Blow My Mind
  • Mama's Love
  • Omodaddy
  • Ife Foju
  • This Year[8]

Àwọn Fíìmù Rẹ̀ àtúnṣe

  • Omoniyun
  • Ogbe Kan Mi
  • Eyin Igbeyawo
  • Love is a six Letter word
  • Vengeance
  • Farugbotayin
  • Mama swagger
  • Tiwa's Story
  • Adeife
  • kokoro okan
  • Iyawo Esu Devils wife
  • Aipejola
  • Oye Oran
  • Ti Tabili Bayi

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Why I visited Ikoyi Correctional Service, Dayo Amusa". The Sun Nigeria. March 20, 2020. Retrieved May 24, 2022. 
  2. Kwentua, Sylvester (December 18, 2021). "Some people have poverty virus not COVID-19 - Dayo Amusa". Vanguard News. Retrieved May 24, 2022. 
  3. "Nollywood Actress Dayo Amusa Drops New Single ‘Blow My Mind’ - Listen". BellaNaija. February 16, 2015. Retrieved May 21, 2022. 
  4. "Actress Dayo Amusa". Daily Trust. April 11, 2022. Retrieved May 21, 2022. 
  5. "Dayo Amusa delights fans, releases Ife Foju off upcoming EP - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. September 3, 2021. Archived from the original on November 25, 2021. Retrieved May 21, 2022. 
  6. "BON Awards 2018: Mercy Aigbe, Tana Adelana shine at 10th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-09. Retrieved 2019-12-23. 
  7. Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2021-10-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "New Music: Dayo Amusa – This Year". BellaNaija. January 21, 2022. Retrieved May 21, 2022.