Deborah Ajakaiye
Wọ́n bí Deborah Enilo Ajakaiye ní ìpínlẹ̀ Plateau ní apá Àríwá Nàìjíríà ní ọdún 1940[1][2] bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ onímọ̀ nípa físíìsì ilé-ayé.orilẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ní obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ ọ̀jọ́gbọ́ nínú físíìsì ní ilẹ̀ Áfíríkà. Iṣẹ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀jẹ́mọ́ físíìsì ilé-àyé tí ran orílẹ̀-èdè yìí lọ́wọ́ nínú ìwàkùsà.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ilé-àyé àti ẹ̀kọ́.
àtúnṣeÒun ló jẹ́ ẹ̀karùn-ún nínú ọmọ kẹfà. Àwọn òbí rẹ̀ gbàgbọ́ nínú fífún ọmọ ní́ ẹ̀kọ́ ìwé, yálà ọkùnrin tàbí obìnrin béè náà ni wọ́n ń pín iṣẹ́ láàárí ọmọkùnri àti ọmọbìnrin. Ní ọdún 962 ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú fisíìsì ní fásítì ìlú Ibadan. Ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní University of Birmingham ìlú England. Ni ọdún 1970, ó gba Ph.D nínú ìmọ̀jẹ́mọ físíìsì ilé-ayé láti Ahmadu Bello University ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìmọ̀ nípa ìṣirò gan-an ni ó wù ú lọ́kan láti ṣe ṣùgbọ́n Ajakaiye sọ́ pé òun kọ́ nípà físíìsì nítorí pé yóò ran orílè-èdè òun lọ́wọ́.[3]
Ajakaiye lọ sí àpẹ́rò àwọn obìnrin tó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ sáyẹ́nsì International Conference of Women Engineers and Scientists tó wáyé ní Cambridge ní ọdún1967. Wọ́n ṣe àtẹ̀jáde awòrán rẹ̀ ní àpérò náà pẹ̀lú àwọn onímọ̀ físíìsì orílẹ̀-èdè Ebun Adegbohungbe, nínú àbájáde The Woman Engineer lórí àpérò náà ní oṣù kéje, ọdún 1967.[4]
Iṣẹ́
àtúnṣeAjakaiye jẹ́ obìnrin ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ físíìsì ní ilẹ̀ Áfíríkà ní ọdún 1980. Ó tí ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ ní fásitì Ahmadu Bello àtiUniversity of Jos, òun ní olórí ẹ̀ka ìmọ̀ sáyẹ́nsì ìṣẹ̀dá ní báyìí. Iṣérẹ̀ pẹ̀lú ìlò-ohun-ìfojúrí-ṣe-físíìsì nih wọ́n lò láti ṣe àwárí àwọn ohun àlùmọ́nì àti omi-ilẹ̀ ní Nàìjíríà. Ó ṣe máàpù òǹfà tí Nàìjíríà[5] pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin rẹ̀.[6] Lẹ́yìn ìfẹ̀yìntì, ó fi àkókò rẹ̀ sẹ Nigeria-based charity, CCWA,[7] èyí tó dásilẹ̀ ní ọdún 1991.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣeOakes, Elizabeth H. (2002). International encyclopedia of women scientists. New York, NY: Facts on File. ISBN 0-8160-4381-7. https://archive.org/details/internationalenc00oake.
- ↑ Onuh, Amara (2017-10-31). "Deborah Ajakaiye: Meet The First Female Physics Professor In Africa". Answers Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-08-15. Retrieved 2019-05-09.
- ↑ "Ajakaiye, Deborah Enilo (c. 1940–) | Encyclopedia.com". www.encyclopedia.com. Retrieved 2021-05-19.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedOakes
- ↑ "International conviviality: recovering women in engineering from Africa and Asia in 'The Woman Engineer'". Electrifying Women (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-02. Retrieved 2022-03-09.
- ↑ Ajakaiye, DE; Burke, K (1973). "A Bouguer gravity map of Nigeria.". Tectonophysics 16 (1): 103–115. Bibcode 1973Tectp..16..103A. doi:10.1016/0040-1951(73)90134-0.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedOakes2
- ↑ CCWA Archived 2022-03-05 at the Wayback Machine. Christian Care for Widows, Widowers, Aged and Orphans.