Dele Belgore
Muhammad Dele Belgore (tí a bí ní ọjọ́ kàrùnlélọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1961) jẹ́ agbejọ́rò àti olósẹ̀lú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni ó dupò fún ipò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara lábẹ ẹgbẹ́ òsèlú Action Congress of Nigeria (ACN) ní ọdún 2011. Ó fìdí rẹmi fún Abdulfatah Ahmed, ẹni tí ó dupò náà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP).[1] Belgore jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ilorin ní Ìpínlẹ̀ Kwara.
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeA bí Belgore sínú ìdílé Lt. Justice Mahmud Babatunde Belgore, Adájọ́ àgbà ilé ẹjọ́ àgbà Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí[2][3][4] àti Alhaja Maryam Alarape Belgore, ẹni tí ó jẹ́ Nọ́sì àti oníṣòwò epo[5][6] Belgore kàwé ní ilé ìwé Nigerian Law School ní ọdún 1985.[7]
Ipa rẹ̀ nínú òsèlú
àtúnṣeẸgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria yan Belgore láti du ipò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara ní ọdún 2011, ṣùgbọ́n ó fìdí remi fún Abdulfatah Ahmed, ẹni tí ó dupò náà lábé ẹgbẹ́ òsèlú Peoples Democratic Party. Belgore yí sí ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party ní ọdún 2013 níbi tí ó ti dupò gómìnà ṣùgbọ́n ó tún fìdí rẹmi ní ọdún 2014.[8][9]
Ó padà sí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress ó sì ṣe àtìlẹyìn fún Abdulrahman Abdulrasaq.[10]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Saraki Senior Demystified – P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "Correction: Former Chief Judge of the Federal High Court, Justice Babatunde Belgore Is Dead | Sahara Reporters". saharareporters.com. Retrieved 2023-06-17.
- ↑ Oyekola, Tunde (2022-12-25). "Kwara govt honours ex-govs, ex-CJN Belgore, Saraki, others". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-17.
- ↑ Olesin, Abdullahi (2022-12-25). "Kwara Honours Founding Fathers As Best Teachers, 5 Others Get Car Prizes" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-17.
- ↑ "Kwara Gov Commiserates with Belgore over Mum's Death – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "You are being redirected...". kwarastate.gov.ng. Retrieved 2023-06-17.
- ↑ ACMC, Edeh Samuel Chukwuemeka (2023-02-24). "Best Lawyers In Nigeria 2023: 14 Most Prominent". Bscholarly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "In Kwara, Belgore, Saraki, ex-VC scramble for PDP guber ticket – Daily Trust". dailytrust.com. 16 November 2014. Retrieved 2023-06-17.
- ↑ "Belgore, ACN ex-governorship candidate joins PDP – P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-17.
- ↑ "Belgore Withdraws from Kwara APC Guber Primary, Directs Supporters to Vote for Abdulrazaq – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-17.