Abdulfatah Ahmed (ojoibi 29 December 1963) jé onísébanki àti òsìsé ìjoba omo Nigeria tó jé lówólówó Gómìnà Ipinle Kwara lati 29 May 2011.

Abdulfatah Ahmed
Governor of Kwara State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2011
AsíwájúBukola Saraki
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kejìlá 1963 (1963-12-29) (ọmọ ọdún 56)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)


ItokasiÀtúnṣe