Diana Ross

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Diana Ernestine Earle Ross (born March 26, 1944[1]) je olorin ati osere ara Amerika. Ross loje olorin asiwaju fun egbe akorin The Supremes ni Motown nigba ewadun 1960. Leyin to fi egbe yi sile ni 1970, Ross bere si ni dakorin be sini o bere si ni se filmu ati ere ni Broadway. O gba idaloruko fun Ebun Akademi bi Osere Obinrin Didarajulo fun ipo ere re bi Billie Holiday ninu filmu Lady Sings the Blues (1972), eyi to gba ebun Wura Olobirikiti fun. O gba opo awon Ebun Orin ara Amerika, idaloruko garnered twelve Ebun Grammy mejila, ati o si gba Ebun Tony fun ere ori-itage re to n je, An Evening with Diana Ross, ni 1977.[2]

Diana Ross
Diana Ross performing at the 2008 Nobel Peace Prize concert in Oslo
Diana Ross performing at the 2008 Nobel Peace Prize concert in Oslo
Background information
Orúkọ àbísọDiana Ernestine Earle Ross
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kẹta 1944 (1944-03-26) (ọmọ ọdún 80)
Ìbẹ̀rẹ̀Detroit, Michigan, U.S.
Irú orinR&B, soul, disco, jazz, pop, dance
Occupation(s)Singer, record producer, actress
Years active1959–present
LabelsLu Pine, Motown, RCA, EMI
Associated actsThe Supremes, The Temptations, The Jackson 5, Marvin Gaye, Michael Jackson, Lionel Richie
Websitewww.dianaross.com


  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-05-04. Retrieved 2011-10-11. 
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-03-15. Retrieved 2011-10-11.