Àdàkọ:Use Nigerian English

Doguwa
Doguwa is located in Nigeria
Doguwa
Doguwa
Location in Nigeria
Coordinates: 10°45′N 8°44′E / 10.750°N 8.733°E / 10.750; 8.733Coordinates: 10°45′N 8°44′E / 10.750°N 8.733°E / 10.750; 8.733
Country Nigeria
StateKano State
Area
 • Total1,473 km2 (569 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total151,181
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
710
ISO 3166 codeNG.KN.DO
Lua error in Module:Mapframe at line 289: attempt to perform arithmetic on local 'lat_d' (a nil value).

Doguwa jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ kan ní Ìpínlẹ̀ Kano lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gúnwà gbùngbùn apá gúsù Ìpínlẹ̀ Kano, tí olú-ìlú rẹ̀ sì wà ní ìlú Riruwa.

Fífẹ̀ rẹ̀ tó 1,473 km2 tí àwọn olùgbé ibẹ̀ sì tó 151,181 gẹ́gẹ́ bí èsì ètò ìkànìyàn ọdún 2006.

Nọ́mbà adání postal code àgbègbè náà jẹ́ 710.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)