End SARS jé iwode ifehonuhan tí àwon odo Nàìjirià láti fopinsi eka olópá orílè-èdè Nàìjirià tí a mò sí SARS àti láti fopinsi ìsì agbara lò eka olopa Nàìjirià, iwode ifehonuhan náà bèrè ní osu kewa 2020 [1] ní ìgbà tí fiimu bí àwon olopa SARS kan sé pa okurin kan farahan lórí ìkànnì ayelujara [2]. Òpòlopò odo Nàìjirià ni o ya sita láti kopa nínú iwode náà, wón sì parapo fehonuhan ní orí èro ayelujara, ní orí ikanni Twitter, "tweet" mejidilogbon millionu titun tí o soro nipa End sars ni ó farahan laarin ijo meji [3], iyori iwode ifehonuhan náà ni pé ìjoba fi opin si eka SARS bí o ti è jé pé wón dá eka miran; SWAT lati ropo won [4]

Àwon ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. Ayitogo, Nasir (2021-10-20). "#EndSARS Anniversary: One year after, what has happened to protesters’ five-point demand?". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-03-03. 
  2. Jones, Mayeni (2021-10-06). "Nigeria’s #EndSars protests: What happened next". BBC News. Retrieved 2022-03-03. 
  3. •, HILLARY ESSIEN; Oluwasanjo, Ahmed (2020-10-11). "#EndSARS surpasses #BlackLivesMatter, packs nearly 30 million tweets in two days". Peoples Gazette. Retrieved 2022-03-03. 
  4. Report, Agency (2020-10-13). "Nigeria Police set up new team to replace disbanded SARS". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-03-03.