Efinrin (Látìnì: Ocimum gratissimum) ni wọ́n tún ń pè ní "clove basil", tàbí "African basil",[1] tí àwọn Hawaii mọ̀ sí "wild basil",[2] jẹ́ ẹ̀yà ewé kan tí ó wà, tí ó sì wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀, Madagascar, apá Gúsù ilẹ̀ Ásíà, ilẹ̀ Bismarck Archipelago, wọ́n ń gbìn ín ní Polynesia, Hawaii, Mẹ́síkò, Panama, West Indies, Bìràsílì, àti orílẹ̀-èdè Bolivia.[3]

Efirin
Ocimum gratissimum
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Tracheophyta
Ẹgbẹ́:
Magnoliopsida
Ìtò:
Lamiales
Ìbátan:
Ociminae
Irú:
Ocimum gratissimum

Orúkọ rẹ̀ ní àwọn èdè mìíràn

àtúnṣe

Efinrin ni wọ́n ewébẹ̀ tàbí egbògi tí ó wọ́pọ̀ jùlọ ní ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀, tí wọ́n sì ń pèé ní àwọn orúkọ wọ̀nyí nínú èdè wọn.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe